Mahmud Shinkafi

Mahmud Shinkafi je oloselu omo ile Naijiria ohun si ni Gomina Ipinle Zamfara[1], tele o je omo egbe oloselu ANPP, loni omo egbe People's Democratic Party ni se. Elesin musulumi pelu iyawo meta.[2]

Mahmud Shinkafi
Governor of Zamfara State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2007
AsíwájúAhmed Sani Yerima


ItokasiÀtúnṣe