Maya (ará Ẹ́gíptì Ayéijọ́un)

Maya ni Olori akapo nigba ijoba awon farao Tutankhamun, Ay ati Horemheb nigba iran-oba ikejidinlogun ni Egipti Ayeijoun.

Statue of Maya and Merit from Leiden
Frontal view of Maya & Merit's statue


Itokasi àtúnṣe