Mokgweetsi Masisi

olóṣèlú àti Ààrẹ Bòtswánà

Mokgweetsi Eric Keabetswe Masisi (ọjọ́ìbí 21 July 1961) ni Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà ìkárùn lọ́wọ́lọ́wọ́, láti ọdún 2018. Ó jẹ́ Alákóso Ètò Ẹ̀kọ́ tẹ́lẹ̀ àti Alákóso Ọ̀rọ̀ iṣẹ́ Ààrẹ àti Ìmójútó Ìgboro láti 2011 di 2014. Wọ́n kọ́kọ́ dìbò yàán sí Ilé-aṣòfin ní 2009.[2][3][4]


Mokgweetsi Masisi
Masisi in 2018
Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà 5k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 April 2018
Vice PresidentSlumber Tsogwane
AsíwájúIan Khama
Chairman of the Botswana Democratic Party
In office
1 April 2017 – 4 April 2018
AsíwájúIan Khama
Arọ́pòSlumber Tsogwane
8th Vice President of Botswana
In office
12 November 2014 – 1 April 2018
ÀàrẹIan Khama
AsíwájúPonatshego Kedikilwe
Arọ́pòSlumber Tsogwane
Member of Parliament for
Moshupa / Manyana
In office
2009 – 1 April 2018
ÀàrẹIan Khama
AsíwájúMaitlhoko Mooka
Arọ́pòKarabo Gare
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Mokgweetsi Eric Keabetswe Masisi

21 Oṣù Keje 1961 (1961-07-21) (ọmọ ọdún 62)
Moshupa, Bechuanaland
(now Botswana)
Ọmọorílẹ̀-èdèMotswana
Ẹgbẹ́ olóṣèlúBotswana Democratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Neo Masisi
ResidenceState House
Alma materUniversity of Botswana
Florida State University
ProfessionTeacher[1]


Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Republic of Botswana - Government portal". www.gov.bw. Archived from the original on 2014-11-29. Retrieved 2017-10-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Guardian, INK Centre for Investigative Journalism, Botswana. "Who is Botswana’s new President Mokgweetsi Masisi?". The M&G Online. Retrieved May 14, 2019. 
  3. "Botswana: Mokgweetsi Masisi takes over presidency amid opposition resurgence | DW | 31.03.2018". DW.COM. Retrieved May 14, 2019. 
  4. "Botswana inaugurates new president Masisi in smooth handover". France 24. Apr 1, 2018. Retrieved May 14, 2019.