Oluwarotimi Odunayo Akeredolu

Olóṣèlú

Oluwarotimi Odunayo Akeredolu, SAN, or Rotimi Akeredolu, (ọjọ́ ìbí 21 July 1956) jẹ́ olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará Nigeria tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ Ondo ní orílẹ̀ edè Nàijíríà lọ́wọ́lọ́wọ̣́. [1] Akeredolu tún jẹ́ ìkan nínú àwọn agbẹjọ́rò àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà (SAN) tí ó sì jẹ́ ààrẹ ẹgbẹ́ amòfin ti orílẹ̀ edè Nàijíríà ní ọdún 2008.[2]

Ọlọ́lájùlọ

Oluwarotimi Odunayo Akeredolu

Oluwarotimi Akeredolu.jpg
Oluwarotimi Akeredolu ní ọdún 2016
Gómìnà Ìpínlẹ Ondo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
ọjọ́ kẹfàdínlọ́gbọn oṣù kejì ọdún 2017
AsíwájúOlusegun Mimiko
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Oluwarotimi Odunayo Akeredolu

21 Oṣù Keje 1956 (1956-07-21) (ọmọ ọdún 66)
Owo, Ìpínlẹ Ondo
Ọmọorílẹ̀-èdèOrílẹ̀ edè Nàijíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
(Àwọn) olólùfẹ́Betty Anyanwu-Akeredolu
Alma materObafemi Awolowo University
OccupationOlóṣèlú
agbẹjọ́rò
Websiteaketi.org

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Breaking Ondo decides Inec officially declares Rotimi Akeredolu Governor elect". www.premiumtimesng.com. Retrieved 27 November 2016. 
  2. "Nigerian Bar". www.nigerianbar.org. Retrieved 27 November 2016.