Ìpínlẹ̀ Mississippi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Bot Fífikún: xal:Мисисип
No edit summary
Ìlà 54:
Ipinle kan ni ile [[USA|Amerika]] ni o n je Mississippi. Awon eniyan ti o wa nibe to 2,217,000. Olu-ilu ibe ni Jackson. Awon ara Panyan-an wa si ile yii ni 1540. Awon ara Faranse wa do si ibe 1699. Awon ara Geesi segun awon Faranse ni 1763. Ni odun 1817 ni Mississippi dara po mo Union. Awon eru po ni ibe o si ni opolopo plantation. O duro ti awon Confederate ninu ioja abele ile Amerika. Odo kan wa ni ipinle yii ti o n je Mississippi. Odo yii ni o gun nju ni ile Amerika. Ti a ba pa odo yii ati Missouri po, awon ni o gun ju ni gbogbo aye. Mississippi gun to maili 2,350.. Oun ati Missouri gun to 3,700 ni ibuso. Odun 1541 ni won se awari Mississippi ni Memphis, Tennessee. Omo ile Panyan-an ti o se awari re ni won n pe ni Hernando de Soto.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
{{ekunrere}}
==Itokasi==
{{reflist}}
{{ipinle amerika}}
 
[[Ẹ̀ka:àwọn Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà]]
 
[[af:Mississippi]]