Onírúiyepúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
Nínú [[mathematics|mathimatiki]], '''oníyèọ̀rọ̀púpọ̀''' kan (''polynomial'') je [[expression (mathematics)|ìgbékalẹ̀ọ̀rọ̀]] kan tó ní ìgún [[Finite set|dídópin]] tó jẹ́ ṣíṣe pẹ̀lú àwọn [[variable (mathematics)|ayípadà]] (tí wọ́n tún jẹ́ [[indeterminate (variable)|aláìmọ̀]]) àti àwọn [[coefficient|olùsọdipúpọ̀]], nípa lílo àwọn ìmúṣe [[addition|ìròpọ̀]], [[subtraction|ìyọkúrò]], [[multiplication|ìsọdipúpọ̀]], àti àwọn [[Exponentiation|agbènọ́mbàga]] nọ́mbà odidi aláìjẹ́ olòdì . Fún àpẹrẹ, {{nowrap|''x''<sup>2</sup> &minus; 4''x'' + 7}} jẹ́ oníyèọ̀rọ̀púpọ̀ kan, sùgbọ́n {{nowrap|''x''<sup>2</sup> &minus; 4/''x'' + 7''x''<sup>3/2</sup>}} kìí ṣe oníyèọ̀rọ̀púpọ̀, nítorípé second [[Term (mathematics)|ọ̀rọ̀]] rẹ̀ kejì jẹmọ́ pínpín pẹ̀lú ''x'' tó jẹ́ ayípadà àti nítorípé ọ̀rọ̀ rẹ̀ kẹta ní agbènọ́mbàga tí kìí ṣe nọ́mbà odidi.
 
Àwọn oníyèọ̀rọ̀púpọ̀ jẹ́ lílò nínú ọ́pọ́lọpọ́ ibi nínú mathimatiki àti sáyẹ́sì. Fún àpẹrẹ, wọn únjẹ́ lílò láti dá àwọn ìṣedọ́gba oníyèọ̀rọ̀púpọ̀, tó ún ṣàmìọ̀rọ̀ ọ̀pọ̀ ìṣòro, láti ìṣòro áljẹ́brà alákọ́bẹ̀rẹ̀ dé ìṣòro tó lọ́jú nínú sáyẹ́nsì; wọ́n únjẹ́ lílò láti túmọ̀ àwọn ìfiṣe oníyèọ̀rọ̀púpọ̀, tí wọ́n le ṣelẹ̀ lọ́pọ̀pọpọ́ ibi bóyá láti nínú basic [[chemistry|kemistri]] àti [[physics|fisiksi]] de [[economics|oro-okowo]] àti [[social science|sáyẹ́nsì àwùjọ]]; wọ́n únjẹ́ lílò nínú [[calculus|kalkulosi]] àti [[numerical analysis|ìtúwò onínọ́mbà]] láti ṣe ìsúnmọ́ àwọn ìfiṣe míràn. Nínú mathimatiki gíga, àwọn oníyèọ̀rọ̀púpọ̀ únjẹ́ líló láti dá àwọn [[polynomial ring|òrùka oníyèọ̀rọ̀púpọ̀]], ajọttúmọ̀ pàtàki nínú [[abstract algebra|áljẹ́brà afòyemọ̀]] àti [[algebraic geometry|jẹ́òmẹ́trì oníáljẹ́brà]].