Onírúiyepúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 4:
 
==Ìgbéwò==
Oníyèọ̀rọ̀púpọ̀ kan le jẹ́ òdo, tàbí kó jẹ́ kíkọ bíi àròpọ̀ ìkan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn [[term (mathematics)|ọ̀rọ̀]] aláìjẹ́ òdo. Iye àwọn ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ jẹ́ adópin. Àwọn ọ̀rọ̀ náà ní nọ́mbà adúróṣinṣin (tó únjẹ́ [[coefficient|olùsọdipúpọ̀]] ọ̀rọ̀ náà) tó le jẹ́ sísọdipúpọ̀ pẹ̀lú nọ́mbà adópin kan ti [[Variable (mathematics)|àwọn ayípadà]] (tó únjẹ́ ṣíṣojú pẹ̀lú lẹ́tà). Àyípadà kọ̀ọ̀kan le ní [[exponent|agbènọ́mbàga]] tọ́ gbọ́dọ̀ jẹ́ nọ́mbà odidi aláìjẹ́ olódì, èyun pé, [[natural number|nọ́mbà àdábá]] kan. Agbènọ́mbàga tó wà lórí ayípadà kan nínú ọ̀rọ̀ kan làúnpè ní [[Degree of a polynomial|ìyí]] ayípadà náà nínú ọ̀rọ̀ náà, ìyí ọ̀rọ̀ náà yíò jé àròpọ̀ àwọn ìyí àwọn àyípadà nínú ọ̀rọ̀ náà, bẹ́ẹ̀sìni ìyí oníyèọ̀rọ̀púpọ̀ kan yíó jẹ́ ìyí ọ̀rọ̀ tí ìyí rẹ̀ bá tóbijùlọ. Nítorípé {{nowrap|''x'' {{=}} ''x''<sup>1</sup>}}, ìyí ayípadà kan tí kò ní agbènọ́mbàga lórí jẹ́ ókan. Ọ̀rọ̀ tí kò ní àyípadà kankan ní únjẹ́ [[constant term|ọ̀rọ̀ adúróṣinṣin]], tàbí "adúróṣinṣin" lásán. Ìyí ọ̀rọ̀ adúróṣinṣin jẹ́ 0. Olùsọdipúpọ̀ ọ̀rọ̀ kan le jẹ́ nọ́mbà yìówù láti inú àkójọpọ̀ pàtó kan. Tí àkójọpọ̀ náà bá jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn nọ́mbà gidi, á so wí pé "àwọn oníyeọ̀rọ̀púpọ̀ tó wà lórí àwọn nọ́mbà gidi". Àwọn irú onírúiyepúpọ̀ tó tún wọ́pọ̀ ni àwọn onírúiyepúpọ̀ tó ní àwọn olùsọdipúpọ̀ oninomba odidi, àwọn onírúiyepúpọ̀ tó ní àwọn olùsọdipúpọ̀ alọ́jú (complex coefficients), àti àwọn onírúiyepúpọ̀ tó ní àwọn olùsọdipúpọ̀ tí wọ́n jẹ́ nọ́mbà odidi [[modular arithmetic|ìfiwọ̀n]] [[prime number|nọ́mbà àkọ́kọ́]] ''p'' kan. Nínú ọ̀pọ̀ àwọn àpẹrẹ nínú abala yìí àwọn olùsọdipúpọ̀ jẹ́ nọ́mbà odidi.
 
Fún àpẹrẹ:
 
: <math> -5x^2y\,</math>
 
jẹ́ ọ̀rọ̀ kan. [[coefficient|Olùsọdipúpọ̀]] rẹ̀ jẹ́ –5, àwọn àyípadà jẹ́ ''x'' àti ''y'', ìyí ''x'' jẹ́ éjì, bẹ́ẹ̀sìni ìyí ''y'' jẹ́ ókan.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}