Onírúiyepúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìlà 21:
Nínú àwọn onírúiyepúpọ̀ tí wọn ní ayípadà kan, àwọn ọ̀rọ̀ wọn únjẹ́ títò gẹ́gẹ́ bíi ìyí wọn, bóyá ní bi "àwọn agbára ''x'' ṣe ún kéré sí", pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó ní ìyí títóbijùlọ níbẹ̀rẹ̀, tàbí ní bí "àwọn agbára ''x'' bá ṣe ún pọ̀ sí". Onírúiyepúpọ̀ nínú àpẹrẹ òkè yìí jẹ́ kíkọ ní bí àwọn agbára ''x'' ṣe ún kéré sí. Ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́ ní olùsọdipúpọ̀ 3 (ẹ́ta), ayípadà ''x'', àti agbénọ́mbàga 2 (éjì). Nínú ọ̀rọ̀ kejì, olùsọdipúpọ̀ {{nowrap|jẹ́ –5}}, ìgbénọ́mbàga jẹ́ ókan . Ọ̀rọ̀ kẹta jẹ́ nọ́mbà adúróṣinṣin. Nítorípé '''ìyí''' onírúiyepúpọ̀ aláìjẹ́ òdo gbọ́dọ̀ jẹ́ ìyí ọ̀rọ̀ tó ní ìyí tótóbijùlọ, onírúiyepúpọ̀ ìgbékalẹ̀ọ̀rọ̀ òkè yìí ní ìyí éjì.
 
Àwọn ọ̀rọ̀ méjì tí wọ́n bá ní àwọn ayípadà tí wọ́n ní àwọn agbára kannáà únjẹ́ "àwọn ọ̀rọ̀ kannáà". Àwọn onírùiyepúpọ̀ únjẹ́ ríròpọ̀ nípa lílo àwọn òfin [[commutative law| commutative]], [[associative law| associative]], àti [[distributive law]], nípa sísopọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ kannáà. Fún àpẹrẹ tí <math>P=3x^2-2x+5xy-2</math> àti <math>Q=-3x^2+3x+4y^2+8</math> nígbànáá <math>P+Q=3x^2-2x+5xy-2+-3x^2+3x+4y^2+8</math> tí a le tún túnkọ báyìí <math>P+Q=x+5xy+4y^2+6</math>.