Onírúiyepúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìlà 22:
 
Àwọn ọ̀rọ̀ méjì tí wọ́n bá ní àwọn ayípadà tí wọ́n ní àwọn agbára kannáà únjẹ́ "àwọn ọ̀rọ̀ kannáà". Àwọn onírùiyepúpọ̀ únjẹ́ ríròpọ̀ nípa lílo àwọn òfin [[commutative law| commutative]], [[associative law| associative]], àti [[distributive law]], nípa sísopọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ kannáà. Fún àpẹrẹ tí <math>P=3x^2-2x+5xy-2</math> àti <math>Q=-3x^2+3x+4y^2+8</math> nígbànáá <math>P+Q=3x^2-2x+5xy-2+-3x^2+3x+4y^2+8</math> tí a le tún túnkọ báyìí <math>P+Q=x+5xy+4y^2+6</math>.
 
Àwọn òfin mẹ́ta yìí náà là únlò láti fi ṣe ìṣọdipúpọ̀ àwọn onírúiyepúpọ̀, nípa fífi ọ̀rọ̀ kọ̀ọ̀kan ti onírúiyepúpọ̀ kan ṣe ìsọdipúpọ̀ ọ̀rọ̀ kọ̀ọ̀kan onírúiyepúpọ̀ kejì. Fún àpẹrẹ tí <math>P=2x+3y+5</math> àti <math>Q=2x+5y+xy+1</math> nígbànáà
:<math>P\times Q=2x\times2x+2x\times5y+2x\times xy+2x\times1+3y\times2x+3y\times5y+3y\times xy+3y\times1+5\times2x+5\times5y+5\times xy+5\times1,</math>
tí a le tún túnkọ báyìí
:<math>PQ=4x^2+21xy+2x^2y+12x+15y^2+3xy^2+28y+5</math>.
 
Àròpọ̀ tàbí àsọdipúpọ̀ àwọn onírúiyepúpọ̀ méjì únjẹ́ onírúiyepúpọ̀.