Olùsọdipúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
Ninu [[mathematics|mathimatiki]] '''olùsọdipúpọ̀''' (Coefficient) ni akopa alassodipupo ninu [[term (mathematics)|oro]] [[expression (mathematics)|igbekaleoroexpression]] kan (tabi ninu [[series|eseese]] kan); lopo igba o le je nomba, sugbon bo ba se je ki i se [[variable (mathematics)|ayipada]] inu igbekale na. Fun apere ninu
:<math>7x^2-3xy+1.5+y</math>
awon oro meteta akoko nitelentele ni awon olusodipupo 7 (éje), −3 (ẹ́ta), ati 1.5 (ókan àtìpín àrún) (ninu oro keta ko si ayipada, bi be olusodipupo gan ni oro fun ra re; a unpe ni [[constant term|oro adurosinsin]] tabi olusodipupo adurosinsin ti igbekaleoro na). Oro to gbeyin, eyun ''y'' ko ni olusodipupo kankan niwaju pato, sugbon a mu pe o ni olusodipupo 1, nitoripe isodipupo re pelu akopa na ko le yipada. Olusodipupo le je nomba, bi ti apere oke yi, sugbon won tun le je paramita inu isoro ti a fe wa ojutu, bi leta bi ''a'', ''b'', ati ''c'' ninu
:<math>ax^2+bx+c</math>
nibi ti a ti mo pe awon wonyi ki se ayipada sugbon olusodipupo.