Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 23:
[[:Image:UN Human Development Report 2007 (2) CBC.svg|('''Color-blind compliant map''') For red-green color vision problems.]]]]
 
'''Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn''' ('''AIE''' tabi '''HDI'''; ''Human Development Index'') je statitiki àkópọ̀jáde tounje lilo lati toipo awon orile-ede bii ipele "idagbasoke eniyan" ati lati pinya awon orile-ede [[developed country|adagbasoke]] (idagbasoke giga), [[developing country|toundagbasoke]] (idagbasoke arin), ati [[underdeveloped|aitodagbasoke]] (idagbasoke kekere). Statistiki na je kikopojade lati inu data lori [[life expectancy|igbe àdúródè]], [[education|eko]] ati per-capita [[GDP|GIO]] tenikookan (gege bi olutoka [[standard of living|iru igbesiaye]]) to je gbigbajo latowo awon orile-ede kookan to si je sise pelu formula yi:
 
* atọ́ka-<math>x</math>-index = <math>\frac{x - \min\left(x\right)}{\max\left(x\right)-\min\left(x\right)}</math>
 
nibi ti <math>\min\left(x\right)</math> ati <math>\max\left(x\right)</math> je iye kikerejulo ati gigajulo ti ayipada <math>x</math> le ni, ni telentele.