Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Simón Bolívar"

6 bytes added ,  09:01, 7 Oṣù Kẹjọ 2010
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Leyin ibori re lori Oba Spein, Bolívar kopa ninu ifidimule isokan awon orile-ede alominira akoko ni Latin America, to je [[Gran Colombia|Gran Kolombia]], to si je Aare re lati 1819 de 1830.
 
Simón Bolívar je mimo ni [[Latin America]] bi akoni, ogboju, olujidide ati atuninigbekun. Nigba igbesiaye soki re o lewaju [[Bolivia]], [[Colombia]], [[Ecuador]], [[Panama]], [[Peru]], ati [[Venezuela]] fun ilominira, o si kopa lati se ifidimule fun [[Democracy|oro oselu]] ni [[Hispanic America|Amerika elede Spani]]. Fun idi eyi won n pe ni "[[George Washington]] ti [[South America|Guusu Amerika]]".<ref>http://www.time.com/time/magazine/article/0,9171,752719,00.html</ref><ref>http://teacherlink.ed.usu.edu/tlresources/units/champions/simonbolivar.pdf</ref>