Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Àwọn Bàhámà"

660 bytes added ,  19:25, 13 Oṣù Kẹjọ 2010
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
|calling_code = [[+1-242]]
}}
'''Àwọn Bàhámà''' ({{pron-en|ðə bəˈhɑːməz|En-us-Bahamas.ogg}}) tabi lonibise bi '''Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ awọn Bàhámà''', je orile-ede elede [[English language|Geesi]] to ni awon [[island|erekusu]] 29, 661 [[cay]]s, ati 2,387 [[islet|erekusu kekere]] 2,387 (apata). O budo si inu [[Atlantic Ocean|Okun Atlantiki]] ni ariwa [[Cuba|Kuba]] ati [[Hispaniola]] ([[Dominican Republic|Dominiki Olominira]] ati [[Haiti]]), ariwaiwoorun awon [[Turks and Caicos Islands|Erekusu Turks ati Caicos]], ati guusuilaorun orile-ede [[United States of America|Awon Ipinle Aparapo ile Amerika]] (nitosi ipinle [[Florida]]). Apapo iye aala ile re je 13,939&nbsp;km<sup>2</sup> (5,382 sq. mi.), pelu idiye olugbe to to 330,000. Oluilu re ni [[Nassau, Bahamas|Nassau]]. Bi jeografi, awon Bahama wa ni asopo erekusu kanna bi [[Cuba|Kuba]], [[Hispaniola]] ([[Dominican Republic|Dominiki Olominira]] ati [[Haiti]]) ati [[Turks and Caicos Islands|Awon Erekusu Turks ati Caicos]].
 
Awon onibudo ibe tele ni awon[[Taino]] ti [[Arawaka]], awon Bahama ni ibi ti Columbus koko gunle si ni Ile Aye Tuntun ni 1492. Botilejepe awon ara Spein ko se amunisin awon Bahama, won ko awon Lucaya abinibi ibe (eyi ni oruko ti awon Taino Bahama unpe ara won) lo si oko eru ni Hispaniola. Lati 1513 de 1650 enikankan ko gbe ori awon erekusu yi, ko to di pe awon olumunisin ara [[United Kingdom|Britani]] lati [[Bermuda]] tedo si erekusu [[Eleuthera]].
 
{{ekunrere}}