Olasope O. Oyelaran: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Olasope O. Oyelaran Oluko imo-eda-ede ni Olasope Oyelaran je ni eka-eko Ede ati litireso Aafirika, OAU, Ife, Nigeria. Lati igba ti won ti da eka-eko yii sile ni 1975 o ti wa ni ibe. ...
 
No edit summary
Ìlà 1:
[[OlasopeArinpe O. OyelaranAdejumo]]
 
Àrìnpé Adéjùmò (2002) Rò óo Re Lagos; The Capstone Publications, ISBN 978 34934 2 6 Ojú-iwé 66.
Oluko imo-eda-ede ni Olasope Oyelaran je ni eka-eko Ede ati litireso Aafirika, OAU, Ife, Nigeria. Lati igba ti won ti da eka-eko yii sile ni 1975 o ti wa ni ibe. Ki o to di igba yii, o ti n sise ni Institute of African Studies, OAU, Ife, Nigeria lati 1970. Oun ni oluko akoko ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika, OAU, Ife, Nigeria. 1988 ni o feyinti ni eka-eko yii.
 
Èèmò Wòlú
 
Níjó Ògún Onírè bá fé mùjè
 
Orí tí ó sunwòn ò rìnde
 
Níjó mòónú ònà bá ń fági
 
Olóríire ò ní rìnnà
 
Mo réèmò níjó abiamo sì rìn
 
Níjó abiamo kàgbákò Ògún
 
Níjó Ògún Onírè gbèmí aboyún tolètolè
 
Àánú abiamo se mi
 
Tèmi sOlúwa oba
 
Sé tònbí ni ká rò
 
Àbí tolè tí ò lésè lórùn
 
E wá wèèmò
 
Níjó aboyún bó lulè lórí òkadà
 
Eléjò tí ń bò leyìn ò tètè tejánu okò
 
Àfi sémú tí táyà dún níkùn aboyún
 
E wá wèèmò
 
Níbi olè inú ti fò jáde lójijì
 
Òlè inú fò jade lójó àìpé
 
Isé abe lèyí àbí nla
 
Okú ìyá nì í lórí títì
 
Òlè inú rè é ní gótà
 
Gìrìgì lérò wó dé
 
Èmi là á se ló gbenu ayé kan
 
Gbogbo abiamo bá tú pùrù sékún
 
N ò rírú èyí rí gbenu tèwe tàgbà
 
Kóówá ń fèpè ránsé sí dérébà ejò...