Àwọn orin ilẹ̀ Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Igbagbo Yoruba nipa ajodun ibile Orin ninu odun ibile Odun ibile Ero Yoruba nipa ajodun ibile ==Orin nínú odún ìbílè == ==Èrò àti ìgbàgbó Yorùbá...
 
Replacing page with 'zukf'
Ìlà 1:
zukf
[[Igbagbo Yoruba nipa ajodun ibile]]
 
[[Orin ninu odun ibile]]
 
[[Odun ibile]]
 
[[Ero Yoruba nipa ajodun ibile]]
 
==Orin nínú odún ìbílè ==
 
==Èrò àti ìgbàgbó Yorùbá nípa àjòdún ìbílè==
Àjòdún ìbílè jé mó bíbo òrìsà kan tí àwon olùsìn rè fi ń wájú móra tàbí láti fi bèbè tàbí san èjé lódò rè. Gbogbo ìwònyí wà fún síse ìfé rè. Àjòdún ìbílè tún lè wà fún ìrántí asááju tàbí akoni kan, bóyá tí ó te ìlú kan dó, tàbí tí ó jagun kan láti gba àwon ènìyàn rè sílè lówó òtá tàbí lówó ibi tàbí ìjànbá kan, tàbí tí ó se ohun mánigbàgbé kan tí won fi ń ránti rè tàbí tí wón fi ń sopé fún un, tí wón sì tí ipa béè so ó di òrìsà tí won yóò máa bo, tí won yóò sì máa se èye fún lódoodún tàbí lóòrèkóòrè. ...
 
[[Agbalogbabo lori orin Yoruba]]
 
[[Iwulo orin Yoruba]]
 
[[Orin Yoruba]]
 
==Àgbálogbábò lori orin==
 
==Ìwúlò orin Yorùbá==
Orin je ònà kan pàtàkì tí ení tí ó korín fí ń gbé èrè-okàn rè jáde lórí ohun tí ń je é lókàn, yálà nípa òrò ara rè, òrò elòmíràn tàbí nípa òrò kan láwùjo.
Òkorin lè fi orin mú iwúrí àti ìdùnu bá ara rè tàbí elòmìíràn. Gégé bí alóre láwùjo, òkorin tàbí òsèré lè fi orin gbé èdùn okàn èrò àwùjo síta, èyí tí ìba máa fún ni ni ìnira tàbí ìtèmólè tàbí ìbánujé abénu, yálà láti owó ìjoba tàbí àwon aláse kan. Orin lè wá fún lílò ara-eni tàbí tí àwùjo lápapò. Orin lè mú ní sapá se ohun tí ó dàbí ení sòroó se fún ní nígbà mìíràn. ...
 
[[Orin apala]]
 
[[Apala]]
 
==Orin Àpàlà ==
 
Ìfáàrà
Orin àpàlà jé òkan lára àwon orin Yorùbá ti wón jé gbájúmò ni agbègbè ègbá, Ìjèbú, Òyò, Òsun àti Ìgbóminà. Orin ayeye ni orin àpàlà, orin ìgbàlóde ni pèlú. Orin àpàlà kò ní nnkan án se pèlú èsìn, òrìsà tàbí ìbo kan tí a mò ni ilè Yorùbá. Orin ìgbàfé ni orin àpàlà....
 
==Orin Fújì ==
 
Ìfáàrà
Orin ìgbàlódé ni orin Fújì. Orin tó gbalágboko ni pèlú. Àwon ohun díè péréte ni a ó sòrò lé lorí nínú orin yìí. A ó fi enu ba ohun èlò orin Fújì, àwon òkorin Fújì ìsàkóso àti kókó tí Fújì ń dálé lórí. ...
 
==Orin Sákárà ==
 
Ìfáàrà
Èdá ìtàn méjì ní a gbó tí ó rò mó bí eré Sákárà se bèrè. Okan ní pé ni ìlú Ìlorin ní Sákárà tí bèrè láti owó àwon Mùsúlùmí kan, kí a to mú un wá sí Ìbàdàn lásìkò Baálè Sítú tí ó jé Olúbàdàn láàrin odún 1914 sí 1925. Èdà ìtàn kejì ní pé eré kerekérè ni ó pilè eré Sakárà láti owó Abúdù, tí ó jé omo Yorùbá kan tí ó ń se àtìpó ní ìlú Bídàá ní ìpínlè Náíjà. ...
 
==Orin Àgan ==
Àwon orin kán wà ni ilè Yorùbá tí wón ń kù lo. Wón ti fi ìgbà kan kári ilè Yorùbá rí. Ní àsìkò yìí ìlú kòòkan ní a ti ń rí won. Won ò tilè kárí ekù kan mó. Irúfé àwon orin náà fara pé òrìsà kan pàtó. Ìlú tí èsìn òkèrè bá ti gba èsìn ìbílè lówó won, dandan ni kí irú orin béè kú pèlú èsìn tí wón gbé jù sílè....
 
==Orin Wéré ==
 
Ìfáàrà
Ìtara àti ìtaníjí nínú èsìn Mùsùlùmí ni a gbó pé ìpilèsè eré ajíwéré, nígbà tí àwon olúfokànsìn kan máa ń lo káàkiri àdúgbò ní ìdájí láti jí àwon Mùsúlùmí lati kírun àárò. Èyí ni aáyan láti má jé kí àwon ènìyàn sùn gbàgbera, kí won sì jí wéré láti sàdúrà òórò....
 
==Orin Jùjú ==
 
==Àwon ohun èlò eré Jùjú==
Nígbà ti eré Jùjú bèrè, àwon ohun èlò tí àwon òsèré n lò ni: báńjò, sèkèrè, samba àti ‘jùjú’ (àsìkò). Nígbà tí won kò lo gìtá alápòótí mo ní wón bèrè síí lo báńjò. Àwon ohun-èlò ìbílé tí wón tún mú wo inú eré Jùjú ni gágan, sákárà tàbí orùn ìsà, gudugudu, agogo, àgídigbo tàbí móló. Àwon ohun-èlò ìgbàlódé tí a mú wónú eré Jùjú ní gìtá, òpò ìlú alásopò tí enìkansoso máa ń lù, bóńgò, kóńgà, èro gbohùngbohùn, míkísà, búsítà, àkódíònù àti dùùrù àfenufon, nígbà kan rí. ...
 
 
==Orin nínú odún ìbílè ==
 
==Èrò àti ìgbàgbó Yorùbá nípa àjòdún ìbílè==
Àjòdún ìbílè jé mó bíbo òrìsà kan tí àwon olùsìn rè fi ń wájú móra tàbí láti fi bèbè tàbí san èjé lódò rè. Gbogbo ìwònyí wà fún síse ìfé rè. Àjòdún ìbílè tún lè wà fún ìrántí asááju tàbí akoni kan, bóyá tí ó te ìlú kan dó, tàbí tí ó jagun kan láti gba àwon ènìyàn rè sílè lówó òtá tàbí lówó ibi tàbí ìjànbá kan, tàbí tí ó se ohun mánigbàgbé kan tí won fi ń ránti rè tàbí tí wón fi ń sopé fún un, tí wón sì tí ipa béè so ó di òrìsà tí won yóò máa bo, tí won yóò sì máa se èye fún lódoodún tàbí lóòrèkóòrè. ...
 
==Iwe ti a yewo==
 
[[Omoniyì Ajíbóyè (2003) Ewì Alohùn Yorùbá Orin Majab Books, Ilorin. ISBN 978 32402 3 4, oju-iwe 95-124.]]
 
[[Omoniyi Ajiboye]]
 
[http://www.researchinyoruba.com link title]