Tutsi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Replacing page with 'kjhgfds'
Ìlà 1:
kjhgfds
[[Tutsi]]
 
Tutsi jé òkan lárà àwon olùgbé meta àwon ènìyàn orílè èdè Rwanda and Burundi. Ìyàtò díè ló wà láàrìn àsà àwon ará Tutisi àti Hutu.
 
Àgbè àti Olùsìn maalu ni isé àárò abínibí àwon ara Tutsi. Maálù jé ohun tí àwon ará Tutsi fi máa ń fi agbára àti Olà won han, èyí ló sì mú àwon ará Tutsi jé Olúborí nínú isé àgbè. Fun bí èédégbèta odún séyin ni Tutusi ti ń se ìjoba lórí àwon tókù
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Tutsi"