Ìranraẹnilọ́wọ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Replacing page with 'dvb'
k Reverted edits by 85.71.93.29 (talk) to last version by Loadewole
Ìlà 1:
[[Self-Help]]
dvb
 
[[Iranraenilowo]]
 
[[Oludare Olajubu]]
 
[[Afolabi ojo]]
Ìwé Àsà ìbílè Yorùbá tí Olóyè Olúdáre Olájubù jé Olóòtu, Ojú-iwé 1-11, Ikeja; Longman Nigeria Limited, 1975.
 
Òjògbón Afolabí Òjó. Àsà Ìran-ara-eni-lówó; Ojú-iwé 158-164.
 
Gégé bí gbogbo wá se mò láti ojó tí aláyé ti dáyé ni àwon èèyàn ti ńran ara won lówó. Bí a ba nsoro nipa ojo tí alaye ti dáyé àwon ti nka ìwé Bíbélì lára wa á fé mú okàn won lo si àkókò tó je pe okùnrin kan soso ló wa lórílè èdè ayé yìí, èyí ni Adamu. Mo rò pé a ò mo gbogbo ise tó se nínú ogbà tí ó wà, sùgbón tí ó bá se eni ti ó mo oúnjeé je nib í èèyan bíi tiwa ni, ó dáni lójú wí pé yíó máa gbìyànjú láti fi owo ká èso igi je ni. Ounje sì nìyí kì í dùn tó béè tó bá se èèyàn nìkan soso ló ńjé é láarò, lósàán àti lálé láti ojo kan dé òsè kan, dé osù kan, dé odún kan. Itan Bíbélì náà so fun wa pé nígbà tí o bùse, Olúwa fi olùrànlówó kan jínkí rè, eléyìí náà ni obinrin tí a ńpè ni Éèfà. O dà bí eni pe inú ogbà Ídénì náà gbádùn si i léhin tí àwon méjèèjì ti wà níbè. Sùgbón orísi ìrànlówó ti wón rí náà kì í se nkan ti kò ní ní ìfàsèhìn-in tirè. Mo fi ìyókù si okàn èyin tí ó jé òjògbón nínú ìwée ti Bíbélì.
 
Ohun tí mo fe fàyo nínú ifisíwájú òrò mi yìí ni pé owó kan kò gbé erù dé orí, a sì ti mò dájú pé bi owó omodé kò se tó pepe bákan náà ní owó àgbàlagbà kò se wo akèrèbè. Béè náà ní àwon olóye èèyàn se máa ńsó fún wa nígbà gbogbo pé ‘òsì we òtun òtún we òsì òun ni owó fi ńmó’. Lórò kan àwon èèyàn ilèe Yorùbá ti gbà á ni àsà kan pàtàkí pé a ní láti máa ran ara wa lówó, kó tó dip é a lè da ohunkóhun oníyebíye kankan se. OrísirísI isé ìran-ara-eni-lówó ni ó wà. Ní ìsèdálèe wa àwon odomokunrin tó bá ti ńfé aya, won a máa ran òbí àfésonà won lówó. Kó tó tilè dip e a bere si í ná owó, eeyan yíó tin a ara sáájú-sáájú. Èyí nip é àwon èèyàn béè lè máa bá àna won lo sí oko láti kolè tàbí láti tun ohun ogbin-in won se. Bákannáà ni won nse ìrànlówó nínú ilé láti kó ilé tuntun tàbí láti tún ilé tí ó bá mbàjé se, bóyá o ńjò ni, tàbí iganna rè ńfé ki a túbò gbe oun dúró dáadáa. Ju gbogbo rè lo, nigbakugbà tí won bá ti ńse irú isé bi eléyìí kìí se eni tí o ńfé àfesónà nìkan soso lo ńse isé bí eléyìí....