Èdè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Replacing page with 'PLEASE REPLACE THIS ARTICLE WITH A NICE PAGE!!!'
k Reverted edits by 58.179.205.72 (talk) to last version by 83.7.83.226
Ìlà 1:
[[Ede Yoruba]]
PLEASE REPLACE THIS ARTICLE WITH A NICE PAGE!!!
 
[[Olalere, Mobolaji Babatunde]]
 
OLALERE MOBOLAJI BABATUNDE
 
ÈDÈ YORÙBÁ
 
Èdè Yorùbá jé èdè kan ti ó gbalè tí ó sì buyì kákàkiri àgbáyé. Ìtàn so fún wa pé ní àgbáyé Kwa ní èdè Yorùbá bátan; kwa jé iyè kan ní Niger Congo. A lèè so pé àwon tí wón ń so èdè Yorùbá yàtò sí orílè èdè Nigeria lé ní Ogbòn nílíònùn, àwon orílè èdè tí a ti ń so èdè Yorùbá yàtò sí Nigeria ni. Togo, Ghana, Serria leone, Brazil, United Kingdom àti United State.
Èdè Yorùbá, * pín sí orísirísi èka* ní àkótán, ó sì ti di gbajúgbájà ni orílè èdè Nìgeria àti àgbáláayé lá papò.
Àwon nnkan tí ó ń gbé èdè Yorùbá níyì.
 
1. Òwe:- Orísirísi ònà ni a le gbà pa òwe:
 
(a) A le pa òwe gégé bí àwon elédè ti ń pa á tàbí bí gbogbo ènìyàn ti ń pá gan-an.
Bí àpeere: Àíyá bé sílè ó bé áré, (igi òún ni kò ga).
 
(b) A le pa owe da, bí àpeere: Ojú kì í ti eégún kí omo alágbàá má korí sóko.
 
(i) Ojú kì í ti eégún nínú aso
 
(ii) Ohun ti i tan leegun odun, omo alagbaa a kori sokò.
 
2. Akànlò èdè
 
3. Lílò àmìn ohùn (´-`).
 
ÌLÒ ÈDÈ YORÙBÁ
 
Àwon èròngbà kòòsí ìlò èdè Yorùbá yíì ni pé mo fé kí àwon akékòó mo èdè Yorùbá lo dáradára nítorí náà a wo ìjúba ni awùjo Yorùbá, a wo ààtò, Ìtúmò, ìlò, àti àgbéyèwò àwon òwe, àkànlò èdè àti òrò àmúlò mííràn. A wo èdè àmúlò nígbà tí a bá ń sòrò àti igba ti a ba ko èdè Yorùbá sile. A wo èbùn sòròsòrò.
A sí wo ìlànà ati òté tó de sísòrò ni àwùjo Yorùbá. A wo ìwúre láwùjo Yorùbá. A wo aáyan àròko kiko. Lábé àròko, a wo aroko wònyí: alapejuwe, ajemoroyin, alalaye, alariiyan, ìsòròngbèsì, onisiipaya, ajemó-ìsonísókí-ìwé ati aroko onileta. A wo bi a se n se agbekale ise to da le girama, iwe atumo, òrò àpilèko, àbò ìpàdé, ìjábò ìwádìí, ìwé ìkéde pélébé àti eyí ti a fi n se ìpolongo ti a máa ń tè mó ara ògiri. Èdè Yorùbá ni ibamu pelu asa obínibí Yorùbá. Ó ye kí a mo òrò í dá sí. Ó ye ki a mo òrò so, ki á si mo òrò ó ko sílè léyìn ìgbà ti a bá ka ìwé kékeré yìí.
 
BÍ ÈDÈ YORÙBÁ NÁÀ SE DI KÍKO SÍLÈ
 
Kí àwon òyìnbó tó dé, kò sí ètò kíko ati kíka èdè Yorùbá. Gbogbo òrò àbáláyé tí ó ti di àkosílè nísinsìnyí nínú opoló àwon baba ńlá wa ni wón wà télè. Irú àwon òrò àbáláyé báyìí a máa súyo nínú orin, ewì àti ìtàn àwon baba wa.
Nígbà tí a kó ń pe gbogbo àwon èyà tí èdè wón papò yìí ní Yorùbá tàbí Yóòbá, won kò fi tara tara fé èyí nítorí pé àwon èyà Yorùbá ìyókù gbà pé àwon Òyó nìkan ni Yorùbá. Nígbà tí àwon òjísé Olórun aláwò funfun tó wá wàásù nípa kírísítì se àkiyèsí pé èdè wón bá ara won mu ni wón bá pè wón ní Yorúbà tàbí Yóòba.
Àwon Yorùbá ti a ko l’éní lo si ilè Améríkà tí a sì wá dá padà sí sàró léhìn tí òwò erú tí tán ni àwon òyìnbó Ìjo C.M.S. kókó so di onígbàgbó.
ABUDA ÈDÈ YORÙBÁ
Àbùdá èdè Yorùbá ni ó máa jé kí á mo ohun tí èdè jé gan-an. Orísirísi ni àwon àbùdá tí èdè Yorùbá ní. Èdè Yorùbá kógo àbùdá wònyí já.
 
(1) Ohun tí a bá pè ní èdè gbódò jé ohun tí a fí ìró èdè gbé jáde. Ìró yìí ni a le pè ní ariwo tí a fi enu pa. A ó se àkíyèsí pé èyí yàtò sí pípòòyì, ijó olóbòùnbòun, dídún tàbí fífò tata tàbí jíjuwó alákàn sí ara won.
 
(2) Èdè nílò kíkó o fún ìgbà pípé díè kí ènìyàn tó le so ó. Ó ti di bárakú tàbí àsà fún wa pé a gbódò kó omo tí a bá sèsè bí ni èdè. Àkiyèsí àti ìwádìí yìí ni àwon eléde gèésì ń góka sí nígbà tí àwón ba so pé “Language is Culturally transmitted”. Omo tí a bá sèsè bí tí a kò kó ní èdè, àti àwùjo jé kòríkòsùn.
 
(3) Ìhun ni èdè ènìyàn gùn lé tàbí dálé. Bí a se hun òrò pò nínú gbólóhùn se pàtàkì kíkà iye ìró èdè nínú gbólóhùn kò fi ibi kankan ní ìtúmò.
 
A lè so pé ìyàndá subú
 
ìyàndá elému subú
 
Ó subú
 
Ìyàndá tí a ti sòrò rè subú.
 
Ìyípadà orírsirísi ló le wáyé sí gbólóhùn wònyí tí yóò sì da ètò won ní, síbèsíbè, yóò ní ìtumò. Irú àbùdá yìí ni onímò èdá-èdè ń pè ní “Structure dependence”.
 
(4) Gbogbo èdè kòòkan ló ní àwon ìró èdè tirè tí a ń pè ní (Fóníìmù {phonemes}). Foniimu yìí sún mó ti àwon eranko sùgbón ó sì tún rò jut i eranko lo. Ó yàtò láti èdè kan sì òmíràn. Bí a bá mú fóníìmù yìí lókòòkan. kì í dá ìtumò ní kó wúlò ìgbà tí a bá kàn án pò mó fóníìmù mìíràn gan-an ló máa sìsé.
Bí àpeere:- ìró èdè /a/ /b/ /d/ /e/ /e/ kò dá ìtumò ní, àfi tí abá kàn wón papò lónà orísirísi. A lè se àkànpò kí á ri òrò bí : abe, baba, adé, alé abbl.
Irúfé àkiyèsí àti ìwádìí yí ni àwon onímò èdà-èdè ń pe gèésì rè ní “duality” tàbí “double articulation” ìwádìí fihàn pé àwon eye àti eranko tí wón ní ìró èdè kò pò, iye èdè tí òkòòkan ní kò pò pèlú. Bí àpeere adìye ní ìró èdè bí ogún, ti mààlúù jé méwàá sùgbón kòlòkòlò ní ogbòn.
 
(5) Èdè jé ohun ètò tí a máa ń lò láti se àròyinlè.
 
ÌWÚLÒ ÈDÈ YORÙBÁ
 
(1) Èdè wúlò fún kí a le bá ara so òrò léyìí tí ó máa ń fa àgbóyé àti àjosepò
 
(2) A máa ń lo èdè láti fi pèsè
 
(3) Èdè la fi ń ko tàbí so ìtàn orísìrísi, ìbáà jé omodé tàbí àgbà.
 
(4) A máa ń fi èdè fa ewà yo nínú afò. Òpòlopò akéwì ni ó máà ń lo èdè Yorùbá ti a ó sì gbédìí fún ewà akéwì náà. A kò le se kí a má kí ara wa ní orísirísi ònà bóyá òré sí òré, pèlú orísirísi ewà èdè.
 
(5) Èdè wúlò fún fífi so èrò okàn wa àti fífi ìtara hàn sí ohun tí a gbó rí tàbí tí ó selè sí wa.
Reference:
 
- Taiwo Olunlade “Èdè Yorùbá àti ìmò èdà èdè”
 
- Taiwo Olunlade “Àgbéyèwò ìlò èdè Yorùbá”
 
Bawoni?
 
[[ar:لغة يوروبا]]
[[br:Yoroubeg]]
[[de:Yoruba (Sprache)]]
[[en:Yoruba language]]
[[eo:Joruba lingvo]]
[[es:Idioma yoruba]]
[[fi:Joruban kieli]]
[[fr:Yoruba]]
[[ja:ヨルバ語]]
[[ka:იორუბა (ენა)]]
[[nl:Yoruba (taal)]]
[[no:Joruba]]
[[pl:Język joruba]]
[[pt:Língua iorubá]]
[[sv:Yoruba (språk)]]
[[wa:Yorouba]]