Siẹrra Léònè: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 64:
}}
'''Siẹrra Léònè''' ({{IPAc-en|icon|s|iː|ˈ|ɛr|ə|_|l|iː|ˈ|oʊ|n}}) ([[Krio language|Krio]]: ''Sa Lone''), lonibise bi '''Orile-ede Olominira ile Siẹrra Léònè''', je orile-ede ni [[West Africa|Iwoorun Afrika]]. O ni bode mo [[Guinea]] si ariwa ati ilaorun, [[Liberia]] ni guusuilaorun, ati Okun Atlantiki ni iwoorun ati guusuiwoorun. Sierra Leone ni aala ile to {{convert|71740|km2|sqmi|0|abbr=on}}<ref name="Sierra Leone">{{cite encyclopedia| url=http://encarta.msn.com/encyclopedia_761563681/Sierra_Leone.html| title=Sierra Leone| author=Encarta Encyclopedia| accessdate=19 February 2008}}</ref> ao si ni olugbe ti idiye re je egbegberun 6.5. O je [[British Colony|Imusin Britani]] tele, loni o ti di [[constitutional republic|orile-ede olominira albagbepo]] to ni awon [[Provinces of Sierra Leone|igberiko meta]] ati [[Western Area]]; awon wonyi na si tun je pipin si [[Districts of Sierra Leone|agbegbe merinla]].
 
Sierra leone ni [[tropical climate|ojuojo olooru]], pelu ile ayika to je orisirisi lati [[savannah]] de [[rainforests]].<ref name="Sierra Leone Geography">{{cite web| url=http://sbs.com.au/theworldnews/Worldguide/index.php3?country=178&header=3| title=Sierra Leone Geography| author=The World Guide| accessdate=19 February 2008}}</ref> [[Freetown]] ni oluilu, ilu totobijulo ati gbongan okowo re. Awon ilu pataki yioku na tun ni [[Bo, Sierra Leone|Bo]], [[Kenema]], [[Koidu|Koidu Town]] ati [[Makeni]].<ref name="Sierra Leone" />
 
Geesi ni [[official language|ede onibise]] nibe,<ref name="Sierra Leone Overview">{{cite web | title =Sierra Leone Overview | publisher=United Nations Development Programme Sierra Leone | url =http://www.sl.undp.org/sloverview.htm | accessdate =3 June 2008}}</ref> ti won unlo ni ile-eko, ibise ijoba ati latowo awon amohunmaworan. [[Mende language|Mende]] ni ede gbangba ti won unso ni guusu, beesini [[Temne language|Temne]] ni ede ti ariwa. [[Krio language|Krio]] (ede Krioli lati inu ede Geesi ati opo awon [[African languages|ede Afrika]] to si je ede abinibi fun [[Sierra Leone Krio people|awon Krio Sierra Leone]]) ni ede akoko ti awon bi 10% olugbe unso sugbon bi 95% ni ede na ye.<ref name="https://eprints.soas.ac.uk/181">https://eprints.soas.ac.uk/181/</ref><ref name="CIA" /> Botilejepe oun je lilo kakiri Sierra Leone, ede Krio ko ni ipo onibise kankan nibe.