Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ìṣeìjọánglíkánì"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
'''Ìṣeìjọánglíkánì''' ('''Anglicanism''') je asa kan ninu [[Christianity|Esin Kristi]] to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo [[Church of England|Ijo ile Ilegeesi]] tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.<ref name="cofe">{{cite web| url=http://www.cofe.anglican.org/faith/anglican/ | title=What it means to be an Anglican | Church of England | accessdate=2009-03-16}}</ref> Oro ''Anglikani'' bi oro wa lati inu ''ecclesia anglicana'', oro inu ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi ''Ijo Ilegeesi (the English Church)''. Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje ''Awon Anglikani''. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara [[Anglican Communion|Idarapo awon Anglikani]] kariaye.<ref name="acomm">{{cite web| url=http://www.anglicancommunion.org/ | title=The Anglican Communion official website - homepage | accessdate=2009-03-16}}</ref>