Deng Xiaoping: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 41:
{{stack elements|end}}
 
'''Deng Xiaoping''' ([[IPA]]pípè: {{IPAc-cmn|AUD|zh-Deng_Xiaoping.ogg|d|eng|4|-|x|iao|3|p|ing|2}}; 22 August 1904 {{ndash}} 19 February 1997) je oloselu, babaalu, aserojinle ati diplomati ara [[People's Republic of China|Saina]].<ref>[http://www.jstor.org/pss/654102 Michael Yahuda: Deng Xiaoping: The Statesman]</ref> Gege bi asiwaju [[Communist Party of China|Egbe Komunisti ile Saina]], Deng je alatunda to siwaju Saina lati sunmo [[market economy|okowo oja]]. Botilejepe Deng ko ni aga gege bi olori orile-ede, olori ijoba tabi [[General Secretary of the Communist Party of China|Akowe Agba Egbe Komunisti ile Saina]] (to je ipo gigajulo ni Saina Onikomunisti), sibesibe o sise bi asiwaju pataki Orileolominira awon Ara saina lati 1978 titi de 1992.