Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Xqbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot Títúnṣe: en:Ijebu-Jesa; cosmetic changes
Unicode
Ìlà 1:
'''Ìjèbú-Jèṣà''' je ilu ni ile [[Naijiria]] ati oluilu agbegbe ijoba ibile Oriade ni [[Ipinle Osun]].
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí ìtàn àtenudénuàtẹnudẹ́nu ni a ti gbógbọ́ nípa ìlú ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà, òròọ̀rọ̀ òkèèrè sì nìyí, bí kò bá lé yóò dín.
ÒkanỌ̀kan nínú àwonàwọn ìtàn náà sosọ pé: OwàỌwà IlésàIléṣà kìíní Ajíbógun àti ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà kìíni, Agírgírì jéjẹ́ tègbóntẹ̀gbọ́n tábúrò. ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà ni ègbónẹ̀gbọ́nOwáỌwájéjẹ́ àbúrò. Bákan náà, tègbóntẹ̀gbọ́n tàbúrò ni ìyá tí ó bí wonwọn. Láti omoomúnọmọomún ni ìyá Ajíbógun OwáỌwá IlésàIléṣà ti kú Ìyá Agígírì tí ó jéjẹ́ ègbónẹ̀gbọ́n ìyá rèrẹ̀ ló wò ó dàgbà, omúnọmún rèrẹ̀ ló sì mún dàgbà. Nípa béèbẹ́ẹ̀ OwáỌwá Ajíbógun àti Agígírì jojọ dàgbà pòpọ̀. Èyí ló mú kí wonwọn di kòrí-kòsùn ara wonwọn láti kékeré wá, wonwọn kí í sì í yara wonwọn bí ó ti wú kí ó rí.
Ìgbà tí wónwọ́n dàgbà tán, tí ó di wí pé wónwọ́n ń wá ibùjókòó tí wonwọn yóò tèdótẹ̀dó, àwonàwọn méjèéji-Agígírì àti ajíbogun yìí náà ló jìjojìjọ dìde láti Ilé-IfeIfẹ. WonWọn wá sí ilèilẹ̀ ÌjèsaÌjẹ̀ṣa láti dó sí kí wonwọn lè ni àyè ijobaijọba tiwontiwọn. Ajíbogun dúró níbi tí a ń pè ní IlésaIléṣa lónìí yìí, òun sì ni OwáỌwá IlésàIléṣà kìíní. Agígírì rìn díèdíẹ̀ síwájú kí ó tó dúró. Lákòókó tí ó fi dúró yenyẹn, ó rò wí pé òun ti rìn jìnnà díèdíẹ̀ sí àbùrò òun kò mòmọ̀ wí pé nnkan ibùsòibùsọ̀ méfàmẹ́fà péré ni òun tí ì rín. SùgbónṢùgbọ́n, lónàlọ́nà kìíní ná, kò féfẹ́ rìn jìnnà púpòpúpọ̀ sí àbúrò rèrẹ̀ gégégẹ́gẹ́ bi ìpinnu wonwọnàwonàwọngbodògbọdọ̀ jìnná sára wonwọn bí ó ti lèlẹ̀ jéjẹ́ wí pé àwonàwọn méjèè jì kò jojọ féfẹ́ gbé ibùdó kan náà. LónàLọ́nà kejì, ò lè jéjẹ́ wí pé bóyá nítorí pé esèẹsẹ̀ lásán tó fi rín nígbà náà tàbí nítorí pé aginjù tó fi orí là nígbà náà ló seṣe rò wí pè ibi tí òun ti rìn ti nàsènàsẹ̀ díèdíẹ̀òdòọ̀dọ̀ àbúrò òun lo seṣe dúró ni ibi tí a ń pè ní IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà lónìí.
wonwọn tó kùrò ni IfèIfẹ̀, wonwọnàádotaàádọta ènìyàn pèlúpẹ̀lú wonwọn, sùgbónṣùgbọ́n ìgbà tí wónwọ́nIlésàIléṣà ti Ajíbógun dúró, ègbónẹ̀gbọ́n rèrẹ̀ fún un ní ogbonọgbọn nínú àádótààádọ́tà ènìyàn náà. Ó ní òun gégégẹ́gẹ́ègbonẹ̀gbọn, òun lè dáàbò bo ara òun, ò sí kó ogún tó kù wá sí ibùdo rè ni IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà. Ìdí nìyí tí a fi ń ki ìlú náà pé;
“Ijẹ̀ṣà ọgbọ̀n
“Ijèsà ogbòn
IjèbúIjẹ̀bú ogún
É sìí bó seṣe a rí
Kógún a paréparẹ́
mógbònmọ́gbọ̀n lára”
Ìtàn míràn sosọ fún wa pé omoọmọ ìyá ni Agígírì àti Ajíbógun ni Ilé-IfèIfẹ̀. Ajíbógun ló lolọ bomi òkun wá fún bàbá wonwọn - olófinọlọ́fin tí ó fójúfọ́jú láti fi seṣe egbogi fún un kí ó lè ríran padà ó lolọ, Ó si bòbọ̀. SùgbónṢùgbọ́n kí ó tó dé àwonàwọn ènìyàn pàápàá àwonàwọn ègbónẹ̀gbọ́n rèrẹ̀ rò wí pé ó ti kú, wónwọ́n sì ti fi bàbá wonwọn sílèsílẹ̀ fún àwonàwọn ìyàwó rerẹ fún ìtójúìtọ́jú. Kí wonwọnlolọ, wónwọ́n pín erùẹrù tàbí ohun ìní bàbá wonwọn líifi nnkan kan sílèsílẹ̀ fún àbúro wonwọn – Ajíbógun. Ìgbà tí ó dé, ó bu omi òkun bòbọ̀, wónwọ́n lo omi yìí, bàbá wonwọn sì ríran.
Ojú Ajíbógun korò, inú sì bi pé àwonàwọn ègbónẹ̀gbọ́n òun ti fi bàbá wonwọn sílèsílẹ̀wónwọ́n sì kó ohun ìnú rèrẹ̀ lolọ. bàbá wonwọn rí i pé inú bí i, ó sì pàrowàpàrọwà fún un. “Omo“Ọmọ àlè ní í rínú tí kì í bí, omoọmọ àlè la ń bèbẹ̀ tí kì í gbó”gbọ́” báyìí ló gba ìpéìpẹ́ (èbèẹ̀bẹ̀) bàbá rèrẹ̀. sùgbónṣùgbọ́n bàbá rèrẹ̀ fun un ní idà kan – Idà AjàségunAjàṣẹ́gun ni, ó ni kí ó máa lé awonawọn ègbónẹ̀gbọ́n rèrẹ̀ lolọ pé ibikíbi tí ó bá bá wonwọn, kí o bèèrè ohun ìní tirètirẹ̀ lówólọ́wọ́ wonwọn. Ó pàsepàṣẹ fún un pé kò gbodògbọdọ̀ pa wónwọ́n. Ajíbógun mú irin-àjò rèrẹ̀ pònpọ̀n, níkehìnníkẹhìn ó bá àwonàwọn ègbónẹ̀gbọ́n rèrẹ̀ ó sì gba òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìní padà lówólọ́wọ́ wonwọn. PèlúPẹ̀lú iséguniṣẹ́gun lórí àwonàwọn arákùnrin rèrẹ̀ yìí, kò ní ìtélórùnìtẹ́lórùn, òun náà féfẹ́ ní ibùjókòó tí yóò ti máa seṣe ìjobaìjọba tirètirẹ̀.
Kò sí ohun tí ó dàbí omoọmọ ìyá nítorí pé okùn omoọmọ ìyà yi púpòpúpọ̀. Agígírí férànfẹ́ràn Ajíbógun owáọwá Obòkun púpòpúpọ̀ nítorí pé omoọmọ ìyá rèrẹ̀ ni. Bàyìí ni àwonàwọn méjèèjì pèrò pòpọ̀ láti fi Ilé - IfèIfẹ̀ sílèsílẹ̀wonwọn sì wá ibùjókòó tuntun fún ara wonwọn níbi tí wónwọ́n yóò ti máa seṣe ìjobaìjọba wonwọn.
Itán sosọ pé Ibòkun ni wónwọ́n kókókọ́kọ́ dó sí kí wonwọn tó pínyà. OwáỌwá gba Òdùdu lolọ, OnaỌna ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà sì gba Ilékéte lolọ. Ó kúrò níbèníbẹ̀ lolọ si EèsúnẸẹ̀sún. Láti EèsúnEẹ̀sún ló ti wá sí Agóró: Agóró yìí ló dúró sí tí ó fi rán LúmòogunLúmọ̀ogun akíkanju kan patàki nínú àwonàwọn tí ó tètẹ̀ lé e pé kí ó lolọ sì iwájú díèdíẹ̀ kí ó lolọ wo ibi tí ilèilẹ̀ bá ti dára tí àwonàwọn lè dó sí. LúmòogunLúmọ̀ogun lelẹ títí bí èmíẹ̀mí ìyá aláró kò padà. ÀloÀlọ rámirámi ni à ń rí ni òrànọ̀ràn LúmòogunLúmọ̀ogun, a kì í rábòrábọ̀ rèrẹ̀. Igbà ti Agígírì kò rí LúmòogunLúmọ̀ogun, ominú bèrèsíbẹ̀rẹ̀sí í kókọ́ óọ́, bóyá ó ti sonùsọnù tàbí erankoẹranko búburú ti pá jejẹ. Inú fun èdòẹ̀dọ̀ fun ni ó fi bóbọ́ sónàsọ́nà láti wá a títí tí òun ó fi rí i. Ibi tí wónwọ́n ti wá a kiri ni wónwọ́n ti gbúròó rèrẹ̀ ni ibì kan tí a ń pè ní ÒkènísàÒkèníṣàÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà lonìí yìí. IyàlenuIyàlẹnu ńlánlà lólọ́ jéjẹ́ fún Agígírì láti rí LúmòogunLúmọ̀ogun pèlùpẹ̀lù àwonàwọn odeọdẹ mélòó kan, Ó ti para pòpọ̀ pèlúpẹ̀lú àwonàwọn odeọdẹ wònyíwọ̀nyí ó sì ti gbàgbé iséiṣẹ́wónwọ́n rán an nítorí ti ibèibẹ̀ dùn mómọ́ on fún owóọwọ́ ìféìfẹ́àwonàwọn odeọdẹ náà fi gbà á. Inú bí Agígírì a sì gbé e bú. SùgbónṢùgbọ́n isàlèisàlẹ̀ díèdíẹ̀ ni òun náà bá dúro sí. Eléyìí ni wónwọ́n seṣe máa ń pe Òkònísà tí wónwọ́n dó sí yìí ní orí ayé. WónWọ́n á ní “Òkènísà orí ayó”.
Agbo ilée BajimonBajimọn ní Òkè -OjàỌjà ni Agígírì sókósọ́kọ́ fi seṣe ibùjókòó. Kò pépẹ́ púpòpúpọ̀ léjìnlẹ́jìn èyí ni ó bá lolọ jà ogun kan, sùgbónṣùgbọ́n kí ó tó padà dé, omoọmọ rèrẹ̀ kan gbà òtéòtẹ́ ńlá kan jojọ tí ó fi jéjẹ́ wí pé Agígírì kò lè padà sí ilée BajimoBajimọ mómọ́. Ìlédè Agígírì kojákọjá sí láti lolọ múlèmúlẹ̀ tuntun tí ó sì kòlékọ̀lé sí Ilédè náà ní ibi tí Aàfin ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú-jèsàjẹ̀ṣà wà títí di òní yìí. Ó jókòó nibènibẹ̀, ó sí pe àwonàwọn tí ó sì jéjẹ́ olóòótóolóòótọ́wónwọ́n múra láti ibé ogun ti omoọmọ rèrẹ̀ náà títí tí wónwọ́n fi ségunṣẹ́gun rèrẹ̀. NikehìnNikẹhìn, omoọmọ náà túnúnbá fún bàbá rèrẹ̀ ati àwonàwọn omoọmọ-ogun rèrẹ̀. “Ojú iná kókọ́ ni ewùrà ń hurun”. EnuẸnu tí ìgbín sì fib ú òrìsàòrìṣà yóò fi lolèlọlẹ̀ dandan ni” OmoỌmọ náà teríbatẹríba fún bàbá rérẹ́ ó sì mòmọ̀ àgbà légbònlégbọ̀n-ónọ́n.
Ìtàn míràn bí a seṣe tetẹ IjèbùIjẹ̀bù-JèsàJẹ̀ṣà dò àti bí a seṣe mòmọ̀ ónọ́n tàbí sosọ orúkoorúkọ rèrẹ̀ÌjèbíÌjẹ̀bí-JèsàJẹ̀ṣà ni ìtàn àwonàwọn akíkanjú tàbí akoniakọni odeọdẹ méje tí wónwọ́n gbéra láti IfeIfẹ láti seṣe odeọdẹ lolọ. WónWọ́n seṣe odeọdẹ títí ìgbà tí wón dé ibi kan, olórí wónwọ́n fi ara pa. WónWọ́n pèrèsìpẹ̀rẹ̀sì í tójúutọ́júu rèrẹ̀ ìgbà tí wónwọ́n seṣe àkíyèsí wí pé ogbéọgbẹ́ náà san díèdíẹ̀, wónwọ́n tún gbéra, wónwọ́nònàọ̀nà-àjò wonwọn pònpọ̀n Igbà tí wónwọ́n dé ibi tí a ń pè ní ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà lónìí yìí ni èjèẹ̀jẹ̀ bá tún bèrèsíbẹ̀rẹ̀sí í sàn jáde láti ojú ogbéọgbẹ́ okùnrinọkùnrin náà. WónWọ́n bá dúró níbèníbẹ̀ láti máa tójútọ́jú ogbà náà, wónwọ́n sì dúró pépẹ́ dìèdìẹ̀. NígbèhìnNígbẹ̀hìn, wónwọ́n fi olórí wónwọ́n yìí síbèsíbẹ̀, wónwọ́n pa àgó kan síbèsíbẹ̀ kí ó máa gbé e. Ìgbà tí àwonàwọn náà bá sodeṣọdẹ lolọ títí, wonwọn a tún padà sódòsọ́dọ̀ olórí wonwọn yìí láti wá tójùu rèrẹ̀ àti láti wá simi lálélálẹ́. WónWọ́n seṣe àkíyèsí pé ìbèìbẹ̀ náà dára láti máa gbé ni wónwọ́n bá kúkú sobèsọbẹ̀ dilé. Ìgbà tí ara olórí wonwọn yá tán, tí wónwọ́nsodeṣọdẹ lolọ títí, ibèibẹ̀ ni wónwọ́n ń fàbòfàbọ̀ sí títí tí ó fi ń gbòrò sí i. OrúkoOrúkọ tí Olórí wonwọn –Agígírì sosọ ibèibẹ̀ ni IJELÚIJẸLÚ nítorí pe ÌJÈÌJẸ̀ ni ÌjèsàÌjẹ̀sà máa ń pe ÈJÈẸ̀JẸ̀. Nigbà tí ìyípadà sì ń dé tí ojú ń là á sí i ni wónwọ́n sosọ orúkoorúkọ ìlú da ÌJÈBÚÌJẸ̀BÚ dípò ÌjèbúÌjẹ̀búwónwọ́n ti ń pè télètẹ́lẹ̀. Agígírì yí ni ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà kiíní, àwonàwọn ìran olódeọlọ́dẹ méje ìjósíìjọ́sí ló di ìdílé méje tí ń jóbajọ́ba ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà títí di òní.
SùgbónṢùgbọ́n IjèbúIjẹ̀bú - ErèẸrẹ̀ ni wónwọ́n kókókọ́kọ́ máa ń pe ìlú yìí rí nítorí erèẹrẹ̀ tí ó seṣe ìdènà fún awonawọn ÒyóỌ̀yọ́. Ó ń gbógun ti ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà nígbà kan. Ní ìlú náà erèẹrẹ̀ seṣe ìdíwóìdíwọ́ fún àwonàwọn jagunjagun ÒyóỌ̀yọ́ ni wónwọ́n bá fi ń pe ìlú náà ni ÌjèbúÌjẹ̀bú - ErèẸrẹ̀. Ní odúnọdún 1926 ni egbéẹgbẹ́ tí a mòmọ̀“Ìjèbú“Ìjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà Progressive Union” yí orúkoorúkọ ìlú náà kúrò láti ÌjèbúÌjẹ̀bú - ErèẸrẹ̀IjèbúIjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà nítorí pé ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà ni ÌjèbúÌjẹ̀bú yìí wa.
A níláti tókatọ́ka sí i pé ÌjèbúÌjẹ̀bú ti ÌjèsàÌjẹ̀ṣà yí lè ní nnkan kan í seṣe pèlúpẹ̀lú ÌjèbuÌjẹ̀bu ti ÌjèbùÌjẹ̀bù –Òde. Bí wónwọ́ntilètilẹ̀ ní orírun kan náà. Ìtàn lè pa wónwọ́n pòpọ̀ nipa àjojéàjọjẹ́ orúkoorúkọ, àjoseàjọṣe kankan lè má sí láàárin wonwọn nígbà kan ti rí ju wí pé orúkoorúkọ yìí, tó wu Ògbóni kìíní ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà nígbà tí ó bá àbúrò rèrẹ̀ Ajíbógun lolọ bòkun, wónwọ́n gba ònàọ̀nà ÌjèbúÌjẹ̀bú-Òde lolọ. IbèIbẹ̀ ló gi mú orúkoorúkọ yìí bòbọ̀ tí ó sì fi sosọ ilú tí òun náà tèdótẹ̀dó.
Nínú àwonàwọn ìtàn òkè yí àwonàwọn méjì ló sosọ bí a seṣe sosọ ìlú náà ní IjèbúIjẹ̀bú sùgbónṣùgbọ́n ó dàbí eniẹni pé a lè gba ti irúféirúfẹ́ èyí tí ó sosọÌjèbúÌjẹ̀bú – Òde ni ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú JèsàJẹ̀ṣà ti mú orúkoorúkọ náà wá ní eléyìí ti ó bójú mi díèdíẹ̀. OrúkoOrúkọ yìí ló wú n tí ó sì sosọ ìlú tí òun náà tèdótẹ̀dóorúkoorúkọ náà. OrúkoOrúkọ oyè rè ni Ògbóni. Itán sosọ fún wa pé ibèibẹ̀ náà ló ti mú un bòbọ̀.
GégéGẹ́gẹ́ bi ìtàn àtenudénuàtẹnudẹ́nu, orísìírísìíoríṣìíríṣìí ònáọ̀ná ni a máa ń gbà láti fi ìdí òótóòótọ́ múlèmúlẹ̀, SùgbónṢùgbọ́n ó kù sówósọ́wọ́ àwonàwọn onímòonímọ̀ òde òní láti seṣe àgbéyèwòàgbéyẹ̀wò àwonàwọn ìtàn wònyíwọ̀nyí kí a sì mú eléyìí tí ó bá fara jojọ òótóọ̀ọ́tólolọ nínú wonwọn.
Nipa pé tègbóntẹ̀gbọ́n tàbúrò ni OwáỌwá IlésàIléṣà àti ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà jéjẹ́ láti àáròàárọ̀ ojóojọ́ wà yìí, sosọ wónwọ́n di kòrí – kòsùn ara wonwọn. WónWọ́n sosọ óọ́ di nnkan ìnira làti ya ara kódà, igbín àti ìkarahun ni wónwọ́n jéjẹ́ sí ara wonwọn. SéṢé bí ìgbín bá sì fà ìkarahun rèrẹ̀ a sèsẹ̀ lé e ni a máa ń gbógbọ́. Ìgbà tí ó di wí pé àwonàwọn tègbóntẹ̀gbọ́n tàbúrò yí máa fi IféIfẹ́ sílèsílẹ̀, ìgbà kan náà ni wónwọ́n gbéra kúrò lóhùnúnlọ́hùnún, apá ibì kan náà ni wónwọ́n sì gbà lolọ láti lolọ tèdótẹ̀dó sí. ÒròỌ̀rọ̀ wonwọn náà wà di ti ajá tí kì í lolọ kí korokoro rèrẹ̀ gbélègbélẹ̀. Ibi tí a bá ti rí ègbónẹ̀gbọ́n ni a ó ti rí abúrò. ÀjoseÀjọṣe ti ó wà láàárìn wónwọ́n pòpọ̀ gan-an tí ó fi jéjẹ́ wí pé ní gbogbo ìlèìlẹ̀ IjèsàIjẹ̀ṣà, ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú -JèsàJẹ̀ṣà àti OwáỌwá IlésàIléṣà jojọàwonàwọn nnkán kan lápapòlápapọ̀ béèbẹ́ẹ̀ náà si ni àwonàwọn ènìyàn wonwọn.
OwáỌwáféfẹ́ fi ènìyàn borèbọrẹ̀ láyé àtijóàtijọ́, ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà gbódògbọ́dọ̀ gbógbọ́ nípa rèrẹ̀.
OwáỌwáféfẹ́ bògúnbọ̀gún, ó ní ipa tí ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà gbódògbọ́dọ̀níbèníbẹ̀, ó sì ní iye ojóọjọ́ tí ó gbódògbọ́dọ̀ lò ní IlèsàIlẹ̀ṣà. Ní ojóọjọ́ àbolégùnúnàbọlégùnún, ìlù ObaỌba ÌjèbuÌjẹ̀bu-JèsàJẹ̀ṣà ni wónwọ́n máa n lù ní IlésàIlẹ́ṣà fún gbogbo àwonàwọn àgbà ÌjèsàÌjẹ̀ṣà làti jó. Nìgbà tí ObaỌba ÌjèbùÌjẹ̀bù -JèsàJẹ̀ṣà bá ń bòbọ̀ wálé léhìnlẹ́hìn òpòọ̀pọ̀ ojóọjọ́ tí ó ti lòlọ̀ ni IlésàIlẹ́ṣà fún odúnọdún ògún, otáforíjofaọtáforíjọfa ni àwònàwọ̀n ènìyàn rèrẹ̀ ti gbódògbọ́dọ̀ pàdé rèrẹ̀. Idí nìyí tí wónwọ́n fi máa ń sosọ pé;
“Kàí bi an kolíjèbúkọlíjẹ̀bú
Níbi an tònàtọ̀nà ÌjèsàáÌjẹ̀sàá bòbọ̀
Ọtáforíjọja ọ̀nà ni an kọlijẹ̀bú
Otáforíjoja ònà ni an kolijèbú
Ọmọ Egbùrùkòyàkẹ̀”
Omo Egbùrùkòyàkè”
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí oyè ni wónwọ́n máa ń jejẹIlésàIléṣàwonwọn sì n jejẹÌjèbúÌjẹ̀bú JèsàJẹ̀ṣà a rí Ògbóni ní IlésàIléṣà béèbẹ́ẹ̀ náà ni ó wà ní ÌjèbúÌjẹ̀bú JèsàJẹ̀ṣà. Ara ÌwàrèfàÌwàrẹ̀fà mefàmẹfà ni ògbóní méjèejì yí a ni IlésàIléṣà sùgbónṣùgbọ́n ògbóni ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà ni asáájúaṣáájú àwonàwọn ìwàrèfàìwàrẹ̀fà náà. A rí àwonàwọn olóyè bí ObaáláỌbaálá, RísàwéRísàwẹ́, ÒdoléỌ̀dọlé, Léjòfi Sàlórò ÀrápatéÀrápatẹ́ àti ObádòỌbádò ni ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣàwónwọ́n ti wà ni IlésàIléṣà.
Bákan náà, orísìírísìíoríṣìíríṣìí àdúgbò ni a rí ti orúkoorúkọ wonwọn bá ara wonwọn mu ní àwonàwọn ìlú méjèèjì yí fún apeereapẹẹrẹ bí a seṣeÒgbónỌ̀gbọ́n ÌlóròÌlọ́rọ̀ ni ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà náà ni a rí i ní IlésàIléṣà, ÒkènísàÒkèníṣà wà ní ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà, ÒkèsàÒkèṣà sì wà ní ìlésàìléṣà. Odò-EsèẸsẹ̀ wà ní ìlú jèèjì yí béèbẹ́ẹ̀ náà ni EréjàẸrẹ́jà pélùpẹ́lù.
Nínú gbogbo àwonàwọn ìlú tí ó wà ní IlèIlẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà, àdè tàbí ohùn ti IlésàIléṣà àti ti IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà ló bá ara wonwọn mu jù lolọ.
ObaỌba IjèbúIjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà ló máa ń fi OwáỌwá tuntun han gbogbo ÌjèsàÌjẹ̀ṣà gégégẹ́gẹ́ bí olórí wonwọn tuntun léhìnlẹ́hìn tí ó bá ti súreṣúre fún un tán.
òkanọ̀kan nínú wonwọn bá sì wàjà, ón ni ogún ti wónwọ́n máa ń jejẹ lódòlọ́dọ̀ ara wonwọn bí aya, erúẹrú àti erùẹrù.
Ní ìgbà ayé ogun, òtúnọ̀tún ogun, ni ÌjèbúÌjẹ̀bú-JèsàJẹ̀ṣà jéjẹ́ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà, wónwọ́n sì ní ònàọ̀nà tiwontiwọn yàtòyàtọ̀ sí ti àwonàwọn yòókù.
Nígbà tí ilèilẹ̀ IlèsàIlèṣà dàrú nígbà kan láyé ojóúnọjọ́ún, àrìmoàrìmọ-kùnrin OwáỌwá àti àrìmoàrìmọ-bìnrin ObaỌba ÌjèbùÌjẹ̀bù-JèsàJẹ̀ṣà ni wónwọ́n fi seṣe ètùtù kí ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà tó rójù ráyè, kí ó tó tùbà tùsetùṣẹ.
Nítorí pé ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú -JèsàJẹ̀ṣà àti OwáỌwá IlésàIléṣà jéjẹ́ tègbóntẹ̀gbọ́n tàbúrò látàáròlátàárọ̀ ojóọjọ́ wá, àjoseàjọṣe tiwontiwọn tún lé igbá kan ju ti gbogbo àwonàwọn obàọbà ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà tó kù lolọ nítorí pé “Owá“Ọwá àti Ògbóni ÌjèbùÌjẹ̀bù -JèsàJẹ̀ṣàmomọ ohun tí wónwọ́n jojọsérùsẹ́rù ara won”wọn”
 
Alaye sókísọ́kí lórí ìlú àti àwonàwọn ènìyàn ìjèbùìjẹ̀bù-jèsàjẹ̀ṣà
 
Ìlù ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà jéjẹ́ ìlú kan pàtàkì ní ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà. IlèIlẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà wà ní ìpínlèìpínlẹ̀ ÒyíỌ̀yị́ ní Nàìjéríà. Apá ìwóìwọ́ oòrùn ni ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà wà ní ilèilẹ̀ Yorùbá tàbí káàárókáàárọ́ - oò- jíire. Ìlú IlésàIlẹ́ṣà ti ó jéjẹ́ olú ìlú fun gbogbo ilèilẹ̀ jèsàjẹ̀ṣà jéjẹ́ nnkan ibùsòibùsọ̀ mérìnléláàádórinmẹ́rìnléláàádọ́rin sí ìlú Ìbàdàn tí jéjẹ́ olú ìlú ìpínlèìpínlẹ̀ ÒyóỌ̀yọ́. Ìlú IjèbúIjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà sì tó nnkan bí ibùsòibùsọ̀ méfàmẹ́fàIlésàIléṣà ní apá àríwá ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà.
 
Ní títóbi, ìlú ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà ni ó powólépọwọ́lé ìlú IlésàIléṣà ilèilẹ̀ IjèsàIjẹ̀ṣà, òun si ni olú ìlú fún ìjobaìjọba ìbílèìbílẹ̀ Obòkun óunọ́unwonwọn tó tún un pín sí ònàọ̀nà mérinmẹ́rin; síbèsíbẹ̀ náà òun ni olú ìlú fún ìjobaìjọba ìbìléìbìlẹ́ ààrin gùngùn obòkun.
 
Àdúgbò márùnún pàtàkì ni wónwọ́n pín ìlú yìí sí kí bà lè rorùnrọrùn fún ètò ìjòbaìjọ̀ba sísesíṣe àti fúniséfúniṣẹ́ ÌlóròÌlọ́rọ̀, ÒkènísàỌ̀kènísà àti Òdògo. ÒkòòkanỌ̀kọ̀ọ̀kan àwonàwọn àdúgbò yí ló ní Olórí omoọmọ tàbí lóógun kòòkankọ̀ọ̀kan tí ó jéjẹ́ asáájúaṣáájú fún omoọmọ àdúgbò rèrẹ̀ òun ní asáájúaṣáájú fún isékíséiṣẹ́kíṣẹ́ àti tí ó bá délèdélẹ̀ láti seṣe ni àdúgbó, béèbẹ́ẹ̀ ni, ó sì tún jéjẹ́ asojúaṣojú obaọba fún àwonàwọn omoọmọ àdúgbò rèrẹ̀. Òdògo nìkan ni kò fi ara mómọ́ èlò yí tó béèbẹ́ẹ̀ nítorí ìtàn tó bí i fi hàn pé ìlú òtòọ̀tọ̀ gédégédé ni òun. ÀwonÀwọn ènìyàn ògbónọ̀gbọ́n náà ń féfẹ́ máa hùwà gégégẹ́gẹ́ bí ìtàn ìgbà ìwásèìwásẹ̀ ti fi hàn wí pé wonwọn kò ní nnkan kan í seṣe pèlúpẹ̀lú ÌjèbúÌjẹ̀bú JèsàJẹ̀ṣà. Lòde òní, nnkan ti ń yàtòyàtọ̀ díèdíèdíẹ̀díẹ̀ nítorí pé àjoseàjọṣẹ tí ó péye ti ń wàyé láàárín ògbónọ̀gbọ́n náà àti àwonàwọn ògbónọ̀gbọ́n yòókù.
 
ÈríẸ̀rí tí ó fi hàn gbegbe pé àwonàwọn ÌjèsàÌjẹ̀ṣà gba ìlù IjèbúIjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà gégégẹ́gẹ́ bi ìlú ti ó tètẹ̀IlésàIléṣà ni ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà ni pé ìjókòó àwonàwọn lóbalóbalọ́balọ́ba ilèilẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà, OwáỌwá ìlèìlẹ̀ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà ni obaọba ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà máa ń yàn àn lé. Síwájú sí i, nípa ti ìlànà oyè jíjejíjẹ, ó ní iye ojóọjọ́OwáỌwá tuntun gbódògbọ́dọ̀ lò ní IjèbùIjẹ̀bù - JèsàJẹ̀ṣà láyé ojóunọjọ́un. ObaỌba ÌjèbùÌjẹ̀bù - JèsàJẹ̀ṣà ni ó máa ń gbé OwáỌwá lésèlésẹ̀ tí ó sì máa ń súreṣúre fún un kí wonwọn tó gbà á gégégẹ́gẹ́owáọwá àti olóri gbogbo obaọba ilèilẹ̀ IjèsàIjẹ̀ṣà.
 
Láti túnbòtúnbọ̀ fi pàtàkì ìlú ÌjèbúÌjẹ̀bú -JèsàJẹ̀ṣà hàn, gégégẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú ìtàn ìwásèìwásẹ̀, ti OwáỌwáféfẹ́ seṣe ìdájóìdájọ́ fún òdarànọ̀daràn apànìyàn kan, ObaỌba ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà gbódògbódọ̀ wà níjòkó, bí èyí kò bà rí béèbẹ́ẹ̀, OwáỌwá gbódògbódọ̀ sùn irú igbéjóigbẹ́jọ́ tábi ìdájóìdájọ́ béèbẹ́ẹ̀ojóọjọ́ iwájú. Ìdí nìyí tí wónwọ́n seṣe máa ń sosọ
 
“Owa“Ọwa ràà dáni í pa
 
K Ìjẹ̀bu -Jẹ̀ṣà mọ mọ̀n
K Ìjèbu -Jèsà mo mòn
 
KówáKọ́wá bá a pani
 
Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà á gbọ́”
Ìjèbú - Jèsà á gbó”
 
IséIṣẹ́ àgbèàgbẹ̀ ni iséiṣẹ́ pàtàkì jùlojùlọàwonàwọn ènìyàn ìlú ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣà ń seṣe. ÒpòlopòỌ̀pọ̀lọpọ̀ wonwọn ni ó jéjẹ́ àgbèàgbẹ̀ alárojealárojẹ, béèbẹ́ẹ̀ ni a tún rí àwonàwọn tó mú àgbèàgbẹ̀ àrojeàrojẹ mómọ́ àgbèàgbẹ̀ agbinrúgbìn tó ń mówó woléwọlé lódóodúnlọ́dọ́ọdún àti láti ìgbàdégbà. ÀwonÀwọn irúgbìn tí wónwọ́n ń gbìn fún àrojeàrojẹ ni, isuiṣu, ègéẹ̀gẹ́ (gbáàgúdá) ikókó, ìresììrẹsì, àgbàdo, kofíkọfí, òwù àti obì sì jéjẹ́ àwonàwọn irù-gbìn tó ń mówó wálé fún wonwọn.
 
A rí àwonàwọn oniseoniṣẹ-owóọwọ́ bíi, alágbèdealágbẹ̀dẹ, onílù. agbégiléreagbẹ́gilére, àwonàwọn molémolémọlémọlé àti àwonàwọn kanlékanlé. ÀwonÀwọn obìnrin wonwọn náà a máa seṣe orísìírísìíoríṣìíríṣìí iséiṣẹ́-owóọwọ́, lára wonwọn ni aró dídá, apeapẹ ati ìkòkò mímomímọ àti asoaṣọ híhun pèlúpẹ̀lú.
 
Bákan náà, wónwọ́n tún jéjẹ́ onísowòoníṣowò gidi. OmoỌmọ ìyá ni elédèẹlẹ́dẹ̀ àti ìmòdòìmọ̀dò, béèbẹ́ẹ̀ náà sì ni inàki àti òboọ̀bọ, gbogbo ibi tí a bá ti dárúkodárúkọ ÌjèsàÌjẹ̀ṣà ni a á ti máa fi ojú onísòwooníṣòwo gidi wò wónwọ́n. Elèyìí ni a fi ń pè wónwọ́n“Òsómàáló”“Òṣómàáló” nítorí kò sí ibi tí a kó ti lè rí ÌjèsàÌjẹ̀ṣà ti òròọ̀rọ̀ ìsòwòìṣòwòdélèdélẹ̀, béèbẹ́ẹ̀ ni kò sí irúféirúfẹ́ owo tí wonwọn kò lè seṣe, ohun tí ó kó wonwọn ni irìnra ni olé àti òleọ̀lẹ. “Alápà má sisé”ṣiṣẹ́” ni àwonàwọn ÌjèsàÌjẹ̀ṣà máa ń pe àwonàwọn ti kò bá lè siséṣiṣẹ́ gidi. WonWọn ko sì férànfẹ́ràn irú àwonàwọn ènìyàn béèbẹ́ẹ̀ ràrá. ÌjèsàÌjẹ̀ṣàkòkọ̀ láti kokọ omoọmọ wonwọn lómolọ́mọ tí ó bá jalè tàbí tí kò níséníṣẹ́ kan pàtàkì lówólọ́wọ́. WònWọ̀n á sí máa fi omoọmọ wonwọn tí ó bá jéjẹ́ akíkanjú tàbí alágbára yangàn láwùjoláwùjọ. “Òkóbò nìkan ni kìí bímobímọ sí tòsí, a ní omoọmọ òun wà ní òkè-òkun” Bákan náà ni pé “arúgbó nìkan ni ó lè paróparọ́ ti a kò lè já a nítorí pé àwonàwọn egbéẹgbẹ́ rèrẹ̀ ti kú tán” PuróPurọ́ n níyì, ètéẹ̀tẹ́ ní ń mú wá, bi iróirọ́ ni, bí òótóòótọ́ ni pé àwonàwọn ÌjèsàÌjèṣà jéjẹ́ akíkanjú, e wo jagunjagun Ògèdèngbé “Agbógungbórò” ÒgbóniỌ̀gbóni Agúnsóyè, “Ologun abèyìngogoúabèyìngọgọú, ó pèfònpẹ̀fọ̀n tán, ó wojú ìdó kòròkọ̀rọ̀, ÒdòfinỌ̀dọ̀fin Arówóbùsóyè, ÒgbókòóndòỌ̀gbọ́kọ̀ọ́ndọ̀ lérí odi kípàyékípàyẹ́yèèyèèyẹ̀ẹ̀yẹ̀ẹ̀ séyìn” Ológun ArímoròArímọrọ̀ àti àwonàwọn OlórúkoOlórúkọ ńláńlá ni ilèilẹ̀ IjèsàIjẹ̀ṣà láyé ojóunọjọ́un. Tí a bá tún wo àwonàwọn onísòwòoníṣòwò ńláńlá lóde òní nílènílẹ̀ Yorùbá jákèjádò, “Okan“Ọkan ni sànpònnáṣànpọ̀nnáláwùjoláwùjọ èpè” ni òròọ̀rọ̀ ti ÌjèsàÌjẹ̀ṣà. Nínú wonwọn ni a ti rí Àjànàkú, Erinmi lókun, OmóleỌmọ́le Àmúùgbàngba bíu ekùnẹkùn, S.B. Bákàrè Olóye méjì léèkanlẹ́ẹ̀kan sosoṣoṣo àti OnìbonòjéOnìbọnòjé àtàri àjànàkù tí kì í serùṣẹrù omodéọmọdé. Mé loòó la ó kà léhínlẹ́hín Adépèlé ni òròọ̀rọ̀ wonwọn.
 
ÀwonÀwọn omoọmọ Ìjèbú -JèsàJẹ̀ṣà jéjẹ́ aláféaláfẹ́ púpòpúpọ̀ pàápàá nígbà tí owóọwọ́ wonwọndilèdilẹ̀. ÀwonÀwọn ènìyàn ti o férànfẹ́ràn àlàáfíà, ìféìfẹ́ àti ìrépòìrẹ́pọ̀ láàárin onílé àti àlejò sì ni wónwọ́n pèlúpẹ̀lú. WonWọn máa ń pín ara wonwọnelégbéjegbéẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ láti seṣe iséiṣẹ́ ìlú láti jojọ kégbékẹ́gbẹ́ àjùmòseàjùmọ̀ṣe lénulẹ́nu iséiṣẹ́ àti orísìírísìíoríṣìíríṣìí ayeyeayẹyẹ nílùú pèlúpẹ̀lú. “Àjèjé owóọwọ́ kan kò gbérùgbẹ́rù dóri” àjùmòsèàjùmọ̀ṣè wonwọn yìí mú ìlosíwájúìlọsíwájú wá fún ìlú náà lópòlópòlọ́pọ̀lọ́pọ̀ “Abiyamo“Abiyamọ kì í gbógbọ́ ekúnẹkún omoọmọ rèrẹ̀ kò má tatí were” ni ti àwonàwọn omoọmọ ÌjèbùÌjẹ̀bù - JèsàJẹ̀ṣà sí ohunkóhun tí wónwọ́ngbógbọ́ nípa ìlú wonwọn. Bí òròọ̀rọ̀ kan bá délèdélẹ̀ nípa iséiṣẹ́ ìlú, wonwọn máa ń rúnpá-rúnsèrúnsẹ̀ sí i, wónwọ́n á sì mú sòkòtò wonwọn wòwọ̀ láti yanjú irú òròọ̀rọ̀ náà. OmoỌmọ okoọkọ ni àwonàwọn omoọmọ ìlú ÌjèbúÌjẹ̀bú - JèsàJẹ̀ṣàtòótòtòótọ̀.
 
Síwájú sí i, orísìírísìíoríṣìíríṣìí ònàọ̀nà tí ó bá òde òní mu ni wónwọ́n ti là sí àárín ilú láìní owóọwọ́ ìjobaìjọba kankan nínú fún ìdàgbàsókè àti ìlosíwájúìlọsíwájú ìlú wonwọn. Fún àpeereàpẹẹrẹ Ilé - ÈkóẸ̀kọ́ gíga (Grammar Schoo) méji tí ó wà ní ilú náà, òógùn ojú wonwọn ni wónwọ́n fi kòkọ̀ wonwọn, béèbẹ́ẹ̀ náà ni Modern School wonwọn. OjàỌjà ilú, ilé-ìfìwé rànsérànṣẹ́ àti gbàngàn ìlú ti o nà wonwọnàádótaàádọ́ta àbòàbọ̀ òkéọ̀kẹ́ naira: ÀwonÀwọn ònàọ̀nà títí tí wónwọ́n bójú mu tí wónwọ́n sì bá ti òde òní mu náà ni wónwọ́n ti fi òógùn ojú wonwọn là láìsí ìrànlówóìrànlọ́wọ́ ìjobaìjọba kankan.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
== Iwe ==
* J.A. Arówóbùsóyè (1982), ‘ITÀN ÌSÈDÁLÈÌSẸ̀DÁLẸ̀ ÌLÚ ÌJÉBÚÌJÉḄÚ-JÉSÀ’ DALL, OAU, IfèIfẹ̀, Nigeria.
 
[[Ẹ̀ka:Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]]