Ìkọ́ni: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: GBADAMOSI TEMITOPE THOMAS ÌKÓNI: TEACHING Kíní a mò sí ìkóni? Ìkóni túmò si ìlànà ti àhún gbà láti fii òye hàn láti ìran kan dé òmírà...
 
Unicode
Ìlà 1:
[[GBADAMOSI TEMITOPE THOMAS]]
 
[[ÌKÓNIÌKỌ́NI: TEACHING]]
 
Kíní a mòmọ̀ìkóniìkọ́ni?
ÌkóniÌkọ́ni túmòtúmọ̀ si ìlànà ti àhún gbà láti fii òye hàn láti ìran kan dé òmíràn àti láti ènìyàn sí elòmíràn. Ní ìdàkejì èwèẹ̀wẹ̀, ìkóniìkọ́ni lèè túmòtúmọ̀ sí ìbáwí tàbí ìtósónàìtọ́sọ́nà láti òdòọ̀dọ̀ enitíẹnití ó ju eniẹni lolọ. ÀmóÀmọ́ ki a máa fi òpáọ̀pá pòòlòpoolopọ̀ọ̀lọ̀pọọlọ pa ejò, ìkónìkọ́n tòní dá lórí ti Òye, ÌmòÌmọ̀ tàbí Èkó.
Tí bá ní kí a woo bi ìtàn ìkóniìkọ́nibèrèbẹ̀rẹ̀, a máa tó òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ odún séyìnsẹ́yìn. Akòleè sosọ pàtó ibi ti ìkóni ti bèrèbẹ̀rẹ̀, nítorí pé orílèorílẹ̀ èdè kòòkànkọ̀ọ̀kàn àti àkójopòàkójọpọ̀ àwonàwọn ènìyàn níbikíbi lóní ìlànà ti wónwọ́n ń gbá kókọ́ àwonàwọn ènìyàn tiwontiwọn. SùgbónṢùgbọ́n orílèorílẹ̀ èdèẹ̀dẹ̀ bíi Gíríìsì (Greece) tí ìsirò ti bèrèbẹ̀rẹ̀, ileilẹ Lárúbáwá (Arabia), ile isreeliisrẹẹli ati béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ, wa nínú àwonàwọn irú ènìyàn tí ó tayotayọ nínú ètò ìkóniìkọ́ni. ÀmóÀmọ́ ètò ìkóniìkọ́ni bí a sè mòmọ̀ ti di àtowódówóàtọwọ́dọ́wọ́ débi wípé olúkúlùkù lóti gbàá ti wónwọ́n sì ti fi tún orílèorílẹ̀ èdè wonwọn tò.
Bí a ti se ń kónikọ́ni se òtòòtòọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láwùjoláwùjọ, bí ati se lèe kókọ́ omodéọmọdé yàtòyàtọ̀ sí bí ati se lèe kókọ́ òdóọ̀dọ́ lángba béèbẹ́ẹ̀ ni ti òdóọ̀dọ́ langba náà yàtòyàtọ̀ sí ti àgbàlàgbà. Gbogbo wa lamòlamọ̀ wí pé omodéọmọdé a máa tètè kókọ́ èkóẹ̀kọ́ láti ibi àwòrán, àwòàwọ̀ àti àfihàn. Nítorí ìdí èyí, àwonàwọn ìwé tí alákòbèrèalákọ̀bẹ̀rẹ̀ bíi aláwìíyé dára púpòpúpọ̀ fún èkóẹ̀kọ́ àwonàwọn omodéọmọdé.
ÈwèẸ̀wẹ̀, tí àwonàwọn omodéọmọdé wònyíwọ̀nyí bá déé ilé èkóẹ̀kọ́ girama ìlànà kíkókíkọ́ àti mímòmímọ̀ wonwọn yóò ti yàtòyàtọ̀ díèdíẹ̀ sí ti ilé èkóẹ̀kọ́ alákòbèrèalákọ̀bẹ̀rẹ̀. Ní pele yìí, a óò tí máa fi yé wonwọnwónwọ́n se leè fi owóọwọ́ ara wonwọn see àwonàwọn ohun tí wónwọ́n ń kó wonwọn wònyíwọ̀nyí, béèbẹ́ẹ̀ gégégẹ́gẹ́ ni wonwọn oo ti máa gbáradì fún ilé èkóẹ̀kọ́ gíga. Ní ilé èkóẹ̀kọ́ girama èwèẹ̀wẹ̀, àwonàwọn ohun ti àwonàwọn akékòakẹ́kọ̀ óò máa há sórí – àkósórí àwonàwọn akékòakẹ́kọ̀ yóò din kù, yàtòyàtọ̀ sí tii ilé èkóẹ̀kọ́ ‘Jéléósimi’.
NjéNjẹ́ tí abá dé ilé èkóẹ̀kọ́ gíga, òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyàtòìyàtọ̀ ni yóò ti wà nínú bi ase ń kónikọ́ni. Ilé èkóẹ̀kọ́ gíga ilé ogbónọgbọ́n, ilé èkóẹ̀kọ́ gíga ilé òmìnira. Ní ilé èkóẹ̀kọ́ gíga akékòakẹ́kọ̀ ní ànfààní lati se ohun tówùú nígbà ti ó bá féfẹ́ tí kòsì olùkóolùkọ́ tí yóò yèéyẹ̀ẹ́ lówólọ́wọ́ wò. ÌkóniÌkọ́ni nílé èkóẹ̀kọ̣́ gíga yàtòyàtọ̀ gédégédé sí ti ilé èkóẹ̀kọ́ girama tàbí alákòóbèrèalákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀.
Ní ilé èkóẹ̀kó gíga, akékòakẹ́kọ̀ ló nílò láti se iséisẹ́ jù, nítorí péé; ní òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, olùkóolùkọ́ yóò kàn wá láti tótọ́ akékòakẹ́kọ̀ sónàsọ́nà ni, akékòakẹ́kọ̀ ni yóò se òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ iséisẹ́ fún ra rèrẹ̀.
ÌkóniÌkọ́ni ni orílèorílẹ̀-èdè yi ti dojú kókọ́ òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsòro tí ósì ti ń se àkóbá fún ètò oròọrọ̀ ajé àti ìdàgbà sókè ilèilẹ̀ yí. Tí abá ni kí áwòó láti ìgbà ìwásèìwásẹ̀ fún àpeereàpẹẹrẹ, ètò ìkóniìkọ́ni dára ni ilé èkóẹ̀kọ́ alákòbèrèalákọ̀bẹ̀rẹ̀, èdè Yorùbá ni afi hún kókọ́ akékòakẹ́kọ̀ láti ilèilẹ̀ kí àtó kii èdè òmíràn bòóbọ̀ọ́, àmóàmọ́ ni báyìí èdè gèésìgẹ̀ẹ́sì ni afi ń kókọ́ akékòakẹ́kọ̀òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ wonwọn si ń sosọ èdè Yorùbá nílé. Èyí lómú kí ó jéjẹ́ wípé òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ kò leè sosọ èdè Yorùbá kó já gaara láì má fii èdè gèésìgẹ̀ẹ́sì kòòkankọ̀ọ̀kan bòóbọ̀ọ́, béènibẹ́ẹ̀ni òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ kò sì leè sosọ èdè gèésìgẹ̀ẹ́sì dáradára. ÒròỌ̀rọ̀ wa dàbíi “eni“ẹni tí ófi àdá pa ìkún, ikún sálosálọ àda tún sonù”sọnù”.
Kí ń tó fí gègéèmi sílèsílẹ̀, gbogbo wa lamòlamọ̀ wí pé ni àìsí ìkóniìkọ́ni kòleè sí ìmòìmọ̀, ni àìsí ìmòìmọ̀ láti ìran kan dé òmíràn; kò leè sí ìdàgbà sókè, ni àìsí ìdàgbà sókè èwèẹ̀wẹ̀, kò leè sí ìlosíwájú, ìlú tí kò bá sì ní ìlosíwájú ti setán láti parun ni. Fún ìdí èyí a óò ri péé ìkóniìkọ́ni jéjẹ́ ohun kan gbógì tí a kò leè fi seré ní àwùjooàwùjọọ wa.
 
 
ÈkóẸ̀kọ́ dára púpòpúpọ̀
 
ÈkóẸ̀kọ́ lóni ayé táawà yi sésẹ́
 
ÈkóẸ̀kọ́ lóhún gbéni dépò gíga
 
ÈkóẸ̀kọ́ lóhún gbéni dépò oláọlá
 
ÈkóẸ̀kọ́ dára púpopúpọ
 
ÈkóẸ̀kọ́ lóni ayé tí awà yí sésẹ́.
 
ÌTÓKASÍÌTỌ́KASÍ (REFERENCE)
 
i. D.F. OdunjoOdunjọ - ‘Alawìye Apa keta’
 
ii. B. Onibonoje – ‘Iwe IkoniIkọni Yorùbá
 
iii. White Shear – ‘ Teaching skills’
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìkọ́ni"