Àwùjọ: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Xqbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot Fífikún: ig:Ȯgbà
Unicode
Ìlà 1:
ÈkóẸ̀kọ́ nípa àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá jéjẹ́ èkóẹ̀kọ́ kan pàtàkì tí kò seṣe é fowófọwọ́ rórọ́ séyìnsẹ́yìn. Kò sí èdáẹ̀dá alààyè tó dá wà láì ní Olùbátan tàbí alájogbé. Orísirísi ènìyàn ló parapòparapọ̀ di àwùjoàwùjọ-bàbá, ìyá, ará, òréọ̀rẹ́, olùbátan ati béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. Bí ìyá seṣe ń bí omoọmọ, tí bàbá ń wo omoọmọ àti bí òréọ̀rẹ́ àti ojúlùmòojúlùmọ̀ seṣe ń báni gbé, béèbẹ́ẹ̀ ni ìbá gbépògbépọ̀ èdáẹ̀dá n gbòòrò si. Gbogbo àwonàwọn wònyíwọ̀nyí náà ló parapòparapọ̀ di àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá. Àti èniẹ̀ni tí a bá tan, àti eniẹni tí a kò tan mómọ́, gbogbo wa náà la parapòparapọ̀ di àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá.
 
ilèilẹ̀ Yorùbá ati níbi gbogbo ti èdáẹ̀dá ènìyàn ń gbé, ìbágbépòìbágbépọ̀ èdáẹ̀dá seṣe pàtàkì púpòpúpọ̀. Bí enìkanẹnìkan bá ní òun ò bá enikéniẹnikẹ́ni gbé, tí kò bá gbé nígbó, yóó wábi gbàlogbàlọ. SùgbónṢùgbọ́n, àwa ènìyàn lápapòlápapọ̀ momọ ìwúlò ìbágbépòìbágbépọ̀. Orísirísi ànfàní ni ó wà nínú ìbágbépòìbágbépọ̀ èdáẹ̀dá.
 
òpòọ̀pọ̀ ènìyàn bá n gbé papòpapọ̀, ó rorùnrọrùn lati jojọ parapòparapọ̀ dojú kokọ ogun tàbí òtéọ̀tẹ́ tí ó bá féfẹ́ wá láti ibikíbi. Yorùbá bòbọ̀ wónwọ́n ní àjòjì owóọwọ́ kan ò gbérùgbẹ́rù dórí. BéèBẹ́ẹ̀ gégégẹ́gẹ́seṣe rí fún àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá. Gbígbé papòpapọ̀ yìí máa ń mú ìdádúró láì sí ìbèrùìbẹ̀rù dání nítorí bí òsùsùòṣùṣù owòọwọ̀ seṣe le láti séṣẹ́, béèbẹ́ẹ̀ ni àwùjoàwùjọ tó fohùn sòkanṣọ̀kan. Èyí jéjẹ́ oun pàtàkì lára ànfàní tó wa nínú ìsòkanìṣọ̀kan nínú àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá. Nídà kejì, bí òròọ̀rọ̀ àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá ba jéjẹ́ kónkó-jabele, ètéẹ̀tẹ́ àti wàhálà ni ojú omoọmọ ènìyàn yóó máa rí. Nítorí náà, ó dára kí ìsòkanìṣọ̀kan jobajọba ni àwujoàwujọ-èdáẹ̀dá.
 
Ìdàgbàsókè tí ó máa ń wà nínú àwùjoàwùjọsèyìnsẹ̀yìn ìfowósowópòìfọwọ́sowọ́pọ̀ bí àti ránmú un gángan ò ti sèyìnsẹ̀yìn èékánná. Ó yeyẹ kí á mò pé nítorí ìdàgbàsókè ni èdáẹ̀dá fi ń gbé papòpapọ̀. Bí igi kan ò seṣe lè dágbó seṣe, béèbẹ́ẹ̀ náà ni enìkanẹnìkan ò lè dálùúgbé. ÒpòlopòỌ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló máa ń dá OgbónỌgbọ́n jojọ fún ìdàgbàsókè ìlú. Bí OgbónỌgbọ́n kan kò bá parí iséiṣẹ́, OgbónỌgbọ́n mìíràn yóó gbè é léyìnlẹ́yìn. Níbi tí orísirísi ogbónọgbọ́n bá ti parapòparapọ̀, ìlosíwájúìlọsíwájú kò ní jìnnà si irú agbègbè béèbẹ́ẹ̀. Gbogbo àwonàwọn nnkan wònyíwọ̀nyí jéjẹ́ ànfàní tó wà ní àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá tí kò sì seṣe é fi sílèsílẹ̀ láì ménumẹ́nu bà.
 
Nínú èkóẹ̀kọ́ nípa àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá, a tún máa ń sòròsọ̀rọ̀ nípa ìsòro tó ń kojú ìbágbépòìbágbépọ̀ èdáẹ̀dá. Kò seṣe é seṣe kó máa sì wàhálà láwùjoláwùjọ ènìyàn. A kò lè ronú lónàlọ́nà kan sosoṣoṣo, nítorí náà, ìjà àti asòasọ̀ máa ń jéjẹ́ àwonàwọn nnkan tí a kò lè sàìṣàì má rì í níbi ti àwonàwọn ènìyàn bá ń gbé. Wàhálà máa ń fa òtèọ̀tẹ̀, òtèọ̀tẹ̀ ń di ogun, ogun sì ń fa ikú àti fífi dúkàá sòfò. ÀwonÀwọn nnkan wònyíwọ̀nyí jéjẹ́ ara àwonàwọn ìsòroìṣòro tó n kojú àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá. Kò sí bí ìlú tàbí orílè-èdè kan kò se ní ní òkanọ̀kan nínú àwonàwọn àwonàwọn ìsòroìṣòro wònyíwọ̀nyí.
 
SùgbónṢùgbọ́n, a gbódò mòmọ̀ wí pé awonawọn ànfàní àti awonawọn ìsòroìṣòro wònyíwọ̀nyí ti wà láti ìgbà pípé wá. Tí a bá wo àwonàwọn ìtàn àtijoàtijọ gbogbo, a ó ri pé gbogbo àwonàwọn nnkan wònyí kò jéjẹ́ tuntun. OgbónỌgbọ́n omoọmọ ènìyàn ni ó fi seṣe okòọkọ̀ orí-ìleìlẹ, ti orí-omi àti ti òfúrifú fún ìrìnkèrindò tí ó rorùnrọrùn. ÀwùjoÀwùjọ-èdáẹ̀dá ti seṣe àwonàwọn nnkan dáradára báyìí náà ni wónwọ́n ń seṣe àwonàwọn ohun tí ó lè pa ènìyàn lára. Fún àpeereàpẹẹrẹ, ìbonìbọn àti àdó-olóró. ÀwonÀwọn ohun ìjà wònyíwọ̀nyí ni wónwọ́n lò ní ogun àgbájé kìnní tí o wáyé ní Odun 1914 sí 1918 àti ti èkejì ní odún 1939 sí 1945. Gbogbo àwonàwọn nnkan wònyíwọ̀nyí ló ti wà tí ó sì tún wà síbè di òní.
 
Lákòótán, èkóẹ̀kọ́ nípa àwùjoàwùjọ-èdáẹ̀dá jéjẹ́ èkóẹ̀kọ́ tó lárinrin. Ohun kan tí a gbódògbọ́dọ̀ mòmọ̀ nip é, kò seṣe é seṣeèdáẹ̀dá máa gbe ní eyoẹyọ kòòkankọ̀ọ̀kan. Ìdí ni pé gbígbé papòpapọ̀ pèlúpẹ̀lú ìsòkanìsọ̀kan àti ìfowósowópòìfọwọ́sowọ́pọ̀ ló lè mú ìtèsíwájúìtẹ̀síwájú àti ìdàgbà-sókè wá
 
{{ekunrere}}
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Àwùjọ"