Kọ́lá Akínlàdé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Unicode
Ìlà 1:
[[Kola Akinlade]]
 
#Ìtàn Ìgbésí Ayé ÒnkòwéÒnkọ̀wé
A bí KóláKọ́lá Akínlàdé ní odúnọdún 1924, ní ìlú Ayétòrò ní [[ìpínlè Ògùn]] ní ilèilẹ̀ [[Nàìjíríà]]. ÀwonÀwọn òbí rèrẹ̀ ni Michel Akínlàdé àti Elizabeth Akínlàdé. Ó lolọ sí ilé-èkóẹ̀kọ́ PóòlùPọ́ọ̀lù mímómímọ́ ní Ayétòrò. LéyìnLẹ́yìn tí ó parí èkóẹ̀kọ́ rèrẹ̀ ní ilé-èkóẹ̀kọ́ yìí ni ó kojákọjá sí Ìlaròó tí ó sì dá iséiṣẹ́ tèwétèwétẹ̀wétẹ̀wé sílèsílẹ̀ ńbèńbẹ̀ fúnrarèfúnrarẹ̀ ni ó ka ìwé gba ìwé-èrí G.C. E. ní ilé.
LéyìnLẹ́yìnKóláKọ́lá Akínlàdé gba ìwé-èríẹ̀rí yìí ni ó dá ìwé ìròyàn kan sílèsílẹ̀ tí ó pe orúkoorúkọ rèrẹ̀‘Ègbádò‘Ẹ̀gbádò Progressive Newspaper: LéyìnLẹ́yìn èyí ni ó wá bèrèbẹ̀rẹ̀ iséiṣẹ́ gégégẹ́gẹ́ bi akòwéakọ̀wé ìjobaìjọba. Ó siséṣiṣẹ́ lábélábẹ́ ìjobaìjọba ìpínlè ìwòìwọ̀-oòrùn àtijóàtijọ́ilèilẹ̀ Nàìjíríà.
KíláKị́lá Akínlàdé lolọ kàwé ní Yunifásítì IfèIfẹ̀ilèilẹ̀ Nàìjíríà ó sì tún padà sí enuẹnu iséiṣẹ́ìpínlèìpínlẹ̀ ìwòìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà. Ní odúnọdún 1976 ni KóláKọ́lá Akínlàdé fèyìnfẹ̀yìn tì. Ní odúnọdún 1980, ó tún gba iséiṣẹ́ olùkóolùkọ́ sí ìbàdàn Boys High School, Ìbàdàn, Nàìjíríà. Ó wá fi èyìnẹ̀yìn tì ní odúnọdún 1984. KóláKọ́lá Akínlàdé ní ìyàwó ó sì bí omoọmọ.
ÒpòlopòỌ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ni KóláKọ́lá Akínlàdé ti kokọ.
Lára wonwọn ni Ajá to ń Lépa EkùnẸkùn, OwóỌ̣wọ̣̣́ TeTẹ AmòokùnsìkàAmòokùnṣìkà, Àgbákò nílé TétéTẹ́tẹ́, BasòrunBaṣọ̀run OlúyòléOlúyọ̀lé, Ajayi, the Bishop, Chaka, the Zulu, Esther, the Queen, Abraham, The…..Friend of God, Sheu Usman Dan fodio, Òwe àti ÌtumòÌtumọ̀ rèrẹ̀, Sàngbá fófọ́, àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. Ó sì tún kópa nínú kíkokíkọ Àsàyàn Ìtàn.
 
#Ìwé ÀsíríÀṣírí AmòòkùnsìkàAmòòkùnṣìkà Tú ní Sókí
 
1. OmoỌmọ ilé-èkóèkọ́ ni Dúró Orímóògùnjé. Ó ku OdúnỌdún kan kí ó jáde ìwé méwàámẹ́wàá. Ìyá rèrẹ̀ kú ní odúnọdún métamẹ́ta séyìnsẹ́yìn, ìyènìyẹ̀n ni pé ó kú ní odúnọdún métamẹ́ta sáájúṣáájú bàbá rèrẹ̀. OmoỌmọ ogótaọgọ́ta odúnọdún ni Bàbá rèrẹ̀ nígbà tí ó kú. Ikú bàbá rèrẹ̀ tí ó gbógbọ́ ní ilé-èkóẹ̀kọ́ ni o gbé e wálé. Ìyàwó mérinmẹ́rin ni Àkàndé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ tí ó jéjẹ́ ìyá Dúró ti kú, ó ku métamẹ́ta. OmoỌmọ márùn-un ni Àkàńgbé Orímóògùnjé bí Dúró sì ni àgbà gbogbo wonwọn. Òun ni àkóbíàkọ́bí. Ìyaa folúké, òkanọ̀kan nínú àwonàwọn ìyàwó wònyíwọ̀nyí, ni ìríjú àkándé, OrímóògùnjeOrímóògùnjẹ, ìyenìyẹn ni pé òun ni ó féranfẹ́ran jù. Ìya fólúké yìí ni ó mú kókórókọ́kọ́rọ́ séèfù jáde tí ó síṣí i tí wonwọn kò sì bá nnkan kan ní ibèibẹ̀. Ìgbà tí Àkàndé mú owó kéyìnkẹ́yìn nínú séèfù yìí kí ó tó kú, owó tí ó wà nínú rèrẹ̀ ju egbàátaẹgbàáta náírà (N30,000.00)lolọ. ÒgbéniỌ̀gbẹ́ni AjúsefínníAjúṣefínní: Òun ní ó ra kòkó lówó Àkàngbé. Ó sanwo ní 10/2/80.
ÀsàkéÀṣàkẹ́: Òun ni ó jérìíjẹ́rìí sí owó kòkó ti Àkàngbé gbà. Ohun tí ó yani lénulẹ́nu ni pé Ogóje náírà (N140.00) péré ni wónwọ́n bá ní abéabẹ́ ìròríìrọ̀rí Àkàngbé nígbà tí ó kú.
Àdùnní: Òun ni ìyá Dúró Orímóògùnjé. Àdùnní ti di olóògbé, ìyenìyẹn nip é ó ti kú.
ÒgbéniỌ̀gbẹ́ni Túndé AtòpinpinAtọ̀pinpin: Òun ló ní kí Dúró fi òròọ̀rọ̀ owó tí ó sonùsọnù lo Olófìn-íntótó.
 
2. Túnde AtòpinpinAtọ̀pinpin náà kokọ létàlẹ́tà sí Olófìn-íntótó. ÌdèraÌdẹ̀ra ni orúkoorúkọ ilé-èkóẹ̀kọ́ àbúrò Túndé AtòpinpinAtọ̀pinpin. OmoỌmọ odúnọdún métàdínlógúnmẹ́tàdínlógún ni Dúró orímóògùnjéorímóògùnjẹ́. ÈgbónẸ̀gbọ́n IlésanmíIlẹ́sanmí ni Àdùnní ìyá Dúró OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. ÀgbèÀgbẹ̀ oníkòkó ni Àkàngbé orímóògùnjéorímóògùnjẹ́, bàbá Dúró nígbà ayé rèrẹ̀. Túndé AtòpinpinAtọ̀pinpin àti ègbónẹ̀gbọ́n rèrẹ̀ máa ń sùn ní ilé Àkàngbé nígbà ti wónwọ́n bá ń lolọ sí ìhà Odò OyaỌya. Dúró OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ nìkan ni omoọmọ tí Àdùnní bé. Ará ìlú Àdùnní ni Olófìn-íntótó, omoọmọ AdésínàAdéṣínà. Túndé Atòpinpin máa ń lolọ gbé ojà ní Èkó. OkòỌkọ̀ ojú omi ni ojàọjà yìí máa ń bá dé.
 
3. Olófìn-íntótó, omoọmọ olusínà kòwékọ̀wé sí Túndé AtòpinpìnAtọ̀pinpìn. ÀròsoÀròsọ ni Olófin-íntótó àti ilésanmí ti wokò. DírébàDírẹ́bà wonwọn ń sáré gan-an ni. Fìlà Olófìn-íntótó tilètilẹ̀sònùsọ̀nùònàọ̀nà. Ó dá mótòmọ́tọ̀ dúró ni kí ó tó lolọ mú un Nígbà tí wónwọ́n dé ojà, dírébà jejẹ èbàẹ̀bà, ilésanmí jejẹ iyán ó sì ra òòyà ní irinwó náírà (400.00)
ojàọjà, Olófìn-íntótó bá obìnrin kan pàdé. Ó ra otíọtí fún un. Obìnrin yìí sì mu ìgò otí kan tán ó sì mu ìkejì dé ìdajì. Ó yeyẹ kí a sesẹ àkíyèsí obìnrin yìí dáadáa nítorí pé òun nì a wá fi hàn gégégẹ́gẹ́eniẹni tí ó jí owó Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ jí ní iwájú.
Nígbà ti Olófìn-íntótó àti Ilésanmí dé Ilé-Ifè tí wonwọn ń lolọ, òdòọ̀dọ̀ Àlàó ni wónwọ́n dé sí. Ilé-IfèIfẹ̀ ni Àlàó ti ń ta ojà. Àlàó ra obì àti otíọtí fún Olófìn-íntótó Olófìn-íntótó mu bíà métamẹ́ta. Àlàó ń mu emuẹmu léyìnlẹ́yìn tí ó jeunjẹun tán Ilésanmú sì ń mu ògógóró. OlófìnỌlọ́fìn-íntótó gbádùn láti máà fi owóọwọ́ pa túbòmutúbọ̀mu rèrẹ̀. Irun tí ó hù sí orí ètè òkè ní ìsàlèìsàlẹ̀ ibi tí imú wà ni ó ń jéjẹ́ túbòmutúbọ̀mu. ÀsàkéÀsàkẹ́: Ó jéjẹ́ òkanọ̀kan nínú àwonàwọn ìyàwó Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. GbajímòGbajímọ̀ ènìyàn ni. OmoỌmọ ogbònọgbọ̀n odúnọdún ni sùgbónṣùgbọ́n ó dàbí omoọmọ odúnọdún mókànlélógúnmọ́kànlélógún. ÒmòwéỌ̀mọ̀wé ni.
Yéwándé: ÒkanỌ̀kan nínú àwonàwọn ìyàwó Àkàngbé ni òun náà. Kò kàwe sùgbónṣùgbọ́n o ní òyàyàọ̀yàyà ó sì máa ń seṣe àyésíàyẹ́sí ènìyàn.
Àlàó: Òun ni Olófin-íntótó àti Ilésanmí dé sí odoọdọ rèrẹ̀. OnígbàgbónOnígbàgbọ́n ni. JòónúJọ̀ọ́nú ni orúkoorúkọ rèrẹ̀ mìíràn. Ó máa ń gbàdúrà ni alaalé kí ó tó sùn. OmoỌmọ métamẹ́ta ni ó bí. Ní ojóọjọ́àwonàwọn Olófin-íntótó kókókọ́kọ́ dé ilé rèrẹ̀wónwọ́n ń gbàdúrà ó ní kí gbgbo wonwọn kokọ orin wá bá mì gbé olúwa. ÀwonÀwọn omoọmọ Àlàó kò bá wonwọn kokọ eseẹsẹ kejì tí ó sosọ wí pé ‘Ojó‘Ọjọ́ ayéè mi ń sáré lolọ sópin’. Àsàmú tí ó jéjẹ́ òkanọ̀kan nínú àwonàwọn omoọmọ Àlàó ni ó seṣe àlàyé fún bàbá rèrẹ̀ ìdí tí wonwọnseṣe kokọ eseẹsẹ kejì orin náà. Ó ní orin àgbàlagbà ni.
 
4. Ilésanmí rórọ́ àlà tí ó lá fún Akin AtòpinpinAtọ̀pinpin omoọmọ OlúsínàOlúṣínà. Ó ní nínú àlá tí òun lá, òún. Rí eniẹni tí ó gbé owó sùgbónṣùgbọ́n òun kò rí ojú rèrẹ̀ tí òun fi ta jí. E jéjẹ́ kí á seṣe àkíyèsí àwonàwọn nnkan wònyíwọ̀nyíwónwọ́n ménumẹ́nu bà ní orí yìí.
Dúró – Òun ni àkóbíàkọ́bí nínú àwonàwọn omoọmọ OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́.
Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún ni
Omo odún métàdínlógún ni
FólúkéFólúkẹ́ - OmoỌmọ Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ni òun náà. OmoỌmọ odúnọdún méwàámẹ́wàá ni. Ó sesèṣẹṣẹ̀ wo kóléjìkọ́lẹ́jì ni.
OmówùmíỌmọ́wùmí- OmoỌmọ Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ni òun náà OmoỌmọ odúnọdún méjomẹ́jọ ni. Ilé-èkóẹ̀kọ́ kékeré ni ó wà.
OládúpòỌládúpọ̀ - - OmoỌmọ Àkàngbé Orímóògùnjé ni òun náà. OmoỌmọ odúnọdún méfàmẹ́fà ni. Ilé-èkoẹ̀kọ kékeré ni ó wà. FólúkéFólúkẹ́, Omówùmí àti OládípòOládípọ̀ jéjẹ́ omoọmọ YéwándéYẹ́wándé. Bándélé jéjẹ́ omoọmọ odún méje. ÀsakéÀṣakẹ́ ni ó bíí YàtòYàtọ̀ sí Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́, Yéwándé nìkan ni ó tún máa ń mu owó nínú séèfù. Àìsàn OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kò ju ojóọjọ́ méwàámẹ́wàá lolọ tí ó fi kú.
Ilé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kò ju ilé kérinkẹ́rin lolọ sí ilé Àlàó. Nígbà tí àwonàwọn Olófìn-íntótó dé ilé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ láti bèrèbẹ̀rẹ̀ ìwádìí. Yéwándé ni ó mú wonwọn woléwọlé KókóróKọ́kọ́rọ́ ojú ńlá séèfù yìí kìí ya OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. AbéAbẹ́ ìròríìrọ̀rí rèrẹ̀ ni ó wà nígbà tí ó ń sàìsànṣàìsàn. Kì í yoyọ kókórókọ́kọ́rọ́ ojú kékeré séèfù.
ÀsàkéÀṣàkẹ́ woléwọléwonwọn níbi tí wonwọn ti ń sòròsọ̀rọ̀ níbi tí wónwọ́n ti ń seṣe ìwádìí nílé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. WónWọ́n máa ń há ìlèkùnìlẹ̀kùn yàrá OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ sùgbónṣùgbọ́n wónwọ́n máa ń fi kókórokọ́kọ́rọ ibèibẹ̀ há orí ìtérígbà. EnikéniẸnikẹ́ni ní inú ilé ni ó lè mú un ní ibèibẹ̀ kí ó sì fi sí ilèkùnilẹ̀kùn
Yéwándé ni ó máa ń tójútọ́jú OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ lóru nígbà tí ó ń seṣe àìsàn. ÀsàkéÀṣàkẹ́ máa ń ràn án lówólọ́wọ́. yéwándé àti àwonàwọn omoọmọ náà máa ń wá tójútọ́jú OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ nígbà ti ó ń sàìsànṣàìsàn lówólọ́wọ́ tí àìsàn rèrẹ̀ bá ń yonuyọnu.
AdékéyeAdékẹ́yẹ ni orúkoorúkọ bàbá yéwándé.
OjàỌjà Ajégbémilékè ni Yéwándé féfẹ́ lolọojóọjọ́okoọkọ rèrẹ̀ kú.
Àlàó ni ó kó ogóje náírà (N140.00) tí wónwọ́n bá níbi ìgbèré OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ fún Yéwándé láti tójú. OrúkoOrúkọ mìíràn tí Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ tún ń jéjẹ́ ni Bándélé. E rántí pé eléyìí yàtòyàtọ̀ sí Bándélé orúkoorúkọ òkanọ̀kan nínú àwonàwọn omoọmọ rerẹ.
ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí ni orúkoorúkọ onísèègùnoníṣèègùn OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. Ó ra páànù ìgàn méjìlá ní òdòọ̀dọ̀ kékeréowó. Èyí sì féfẹ́ mí ìfura dání nítorí owó tí ó sonù. ÀwonÀwọn kan rò pé bóyá òun ni ó jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ tí ó sonùsọnù.
Nílé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ níbití wónwọ́n ti ń seṣe ìwádìí, OlófìnỌlọ́fìn-íntótó rí èjáẹ̀já òwú kan tí ó wà lára òkanọ̀kan nínú àwonàwọn ojú kéékèèkéé inú séèfù ó sì mú un. Gbòngán ni folásadéfọláṣadé ìyàwó àfékéyìnàfẹ́kẹ́yìn OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ń gbé. Ó máa ń lò tó ojóọjọ́ márùn-ún tàbí òsèọ̀sẹ̀ kan ní ifèifẹ̀ ní ilé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kí ó tó padà sí GbòngánGbọ̀ngán. Kò bímobímọ kankan fún Orímóògùnjé. Ó yeyẹ kí a seṣe àkíyèsí folásadéfọláṣadé dáadáa nítorí pé òun ni Olófìn-íntótó ra otí fún ní ojàọjà tíó mu ìgò otíọtí kan àbò. Òun ni a sì rí ní òpin ìwé pé òun ni ó jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ gbé.
 
5. OmótósòóỌmọ́tọ́ṣọ̀ọ́sítóòsítọ́ọ̀. KáyòdéKáyọ̀dé ni orúkoorúkọ akòwéakọ̀wé rèrẹ̀. Ó ti tó odúnọdún méfàmẹ́fà kí Akin OlófínỌlọ́fín-íntótó omoọmọ OlúsínàOlúṣínà àti OmótósòóỌmọ́tọ́ṣọ̀ọ́ ti rí ara wonwọn momọwonwọn tún tó rí ara wonwọn yìí. Àbúrò OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ni Ilésanmí tí òun àti Olófìn-íntótó jojọseṣe ìwádìí ní ilé-Ifè. ÒréỌ̀rẹ́ OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ni AjísefínníAjíṣefínní tí ó ń ta kòkó. BíoláBíọlá ni orúkoorúkọ eniẹni tí ó ń ta otíọtí
LóòótóLóòótọ́, onísèègùnoníṣèègùn ni ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí síbèsíbẹ̀, kò wowọ egbéẹgbẹ́ àwonàwọn OnísèègùnOníṣèègùnorúkoorúkọ rèrẹ̀ ń jéjẹ́ EgbéẸgbẹ́ ìlera loògùn OròỌrọ̀.
AwóyemíAwóyẹmí ni orúkoorúkọ eniẹni tí ó bá àwonàwọn OlófìnỌlọ́fìn-íntótó níbi tí wónwọ́n ti ń gbádùn lódòlọ́dọ̀ OmotósòóỌmọtóṣọ̀ọ́.
Ilésanmí àti OlófinỌlọ́fin-íntótó sosọ nípa ara wonwọnàwonàwọn momọ ilèilẹ̀ tètẹ̀ múyémúyẹ́ (E rántí pé iséiṣẹ́ òtelèlmúyéọ̀tẹlẹ̀lmúyẹ́ ni wónwọ́n ń seṣe). AjúsefínníAjúṣefínní, òréọ̀rẹ́ orímóògùnjéorímóògùnjẹ́ ni ó bá OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ra ilèilẹ̀ tí ó ń kókọ́ ilé sí. A ó rántí pé kòkó ní AjísefínníAjíṣefínní ń tà.
OwóỌwọ́ ÒsúnlékèÒṣúnlékè ni wónwọ́n ti r ailèailẹ̀OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ fi ń kólé náà. EgbètaẸgbẹ̀ta náírà (N600.00) ni wónwọ́n ra ilèilẹ̀ náà.
Káyòdé akòwé OmótósòóỌmọ́tọ́ṣọ̀ọ́ sùn ní enuẹnu iséiṣẹ́ Ìgbà tí wónwọ́n bi í pé kí ló dé tí ó fi sùn ni ó dáhùn pé olè ajérangbeajẹ́rangbeàwonàwọn ń lé ní òru ni kò jéjẹ́àwonàwọn sùn dáadáa. Ó yeyẹ kí á seṣe àkíyèsí pé OnísèègùnOníṣèègùn ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí ni olórí àwonàwọn olè ajérangbéajẹ́rangbé yìí gégégẹ́gẹ́ bí a ó seṣe rí i kà ní iwájú. EranẸran tí ó ń jí gbé yìí wà lára ohun tí ó jéjẹ́àwonàwọn ènìyàn fura sí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí pé òun ló jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ gbé níbi tí ó tí ń tójútọ́jú rèrẹ̀ nígbà tí ó ń seṣe àìsàn.
EranẸran métamẹ́ta ni wónwọ́n bá ní ilé àwonàwọn olè wònyíwọ̀nyí nítorí pé wónwọ́n ti jí méjì télètẹ́lẹ̀. Nítorí pé ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí jéjẹ́ ògáọ̀gá fún àwonàwọn olè wònyíwọ̀nyí, wónwọ́n mú un lolọÀgóÀgọ́ olópàáọlọ́pàá tí ó wà ní Morèmi ní ilé-Ifè.
 
6. Nígbà ti OlófìnỌlọ́fìn-íntótó gbógbọ́wónwọ́nÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbíàgóàgọ́ olópàáọlọ́pàá Morèmi, òun àti Ilésanmí lólọ́ibèibẹ̀. Aago méfàmẹ́fàméjomẹ́jọ ni ògáọ̀gá olópàáọlọ́pàá máa ń rí ènìyàn sùgbónṣùgbọ́n ó gbà láti rí Akin àti Ilésanmí léyìnlẹ́yìn ìgbà tí ó ti rí káàdì Akin.
PópóoláPópóọlá ni orúkoorúkọ ògáọ̀gá olópàáọlọ́pàá yìí. ÒréỌ̀rẹ́ Akin Olófìn-íntótó, omoọmọ OlúsínàOlúṣínà ni. Àbéòkúta ni PópóoláPópóọlátèlètẹ̀lẹ̀wónwọ́n tí wá gbé e wá sí Morèmi ní IfèIfẹ̀ níbi tí ó ti jéjẹ́ ògáọ̀gá àwonàwọn olópàáọlọ́pàá ibèibẹ̀. Ó ti tó odúnọdún métamẹ́ta tí ó ti rí Akìn momọ. PópóoláPópóọlá bèèrè Túndé AtòpinpinAtọ̀pinpin lówólọ́wọ́ Akin.
LéyìnLẹ́yìn ìgbà tí wónwọ́nwónwọ́n ti sèṣè àlàyé pé òróọ̀rọ́ ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbíwónwọ́n mú ni ó gbé àwonàwọn wa ni wónwọ́n seṣe àlàye pé tí ó bá jéjẹ́ pé òun ni ó jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́, yóò ti ná tó egbèjoẹgbẹ̀jọ náírà (N1,600.00) nínú owó náà. EranẸran ti ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí jí gbé ni ó jéjẹ́wónwọ́n ní ànfààní láti yeyẹ ilé rèrẹ̀ wo.
ÀwonÀwọn òròọ̀rọ̀ kan wà tí àwonàwọn ènìyàn sosọ ní orú yìí tí ó yeyẹ kí á seṣe àkíyèsí.
Ilésanmí ni ó korinkọrin pé, ‘Iyán lóunjelóunjẹ.’
Akin ni ó sosọ pé, Ajímutí kìí tí’
Akin náà ni ó sosọ pé, ‘Eni‘Ẹni fojú di Pópó á gba póńpó lórí…’. Orúko PópíoláPópíọlá ni ó fi ń seréṣeré níbí yìí.
PópóoláPópóọlá sosọ pé, ‘Eni‘Ẹni tí ó pe tóró, Á senuṣẹnu tóńtótọ́ńtọ́..’ Ó yeyẹ kí á seṣe àkíyèsí pé Àlàó ni oríkì PópóoláPópóọlá. Eléyìí yàtò sí Àlàó tí ó tójú àwonàwọn Olófìn-íntótó tí a ti seṣe àkíyèsí rèrẹ̀ sáájúṣáájú.
Nígbà tí wónwọ́nyeyẹ ilé ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí wò, owó tí wónwọ́n bá ní ibèibẹ̀ jéjẹ́ ogósànọgọ́sàn-án náírà (N180.00) Níní orí yìí, a ó rí òwe, ‘Àfàgò kéyinkẹ́yin àparò…’ Ohun tí ó fa òwe yìí ni eranẹranÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí jí gbé àti èwònẹ̀wọ̀nwónwọ́n ní yóò lolọ tí ìyàwó rèrẹ̀ yóò sì ti bímobímọ kí ó tó dé. Àpatán òwe yìí ni, ‘Afàgò kéyinkẹ́yin àparò, ohun ojú ń wá lojú ń rí.
 
7. Akin OlúsínàOlúṣínà àti Ilésanmí lolọ sí ilé ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí. Nígbà tí wónwọ́nibèibẹ̀, òògùn ni ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbíseṣe. Orí yìí ni a ti momọ ìdí tí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí fi férànfẹ́ràn OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. Ìdí tí ó fi férànfẹ́ràn rèrẹ̀ nip é nígbà tí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí ń seṣe òkú ìyá rèrẹ̀, ó fún un ní ogórùnọgọ́rùn-ún náírà (N100.00) níbi tí kò ti sí eniẹni tí ó tún fún un ju náírà márùn-ún lolọ.
Àlàó tí ó tójútọ́jú Akin àti Ilésanmí nígbà tí wónwọ́nIfèIfẹ̀féranfẹ́ran oògùn ìbílèìbílẹ̀
ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí sosọOrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kì í finú tan Àlàó yìí ÀwonÀwọn ohun tí ó tún yeyẹ kí á seṣe àkíyèsí ní orí yìí ni ìwònyíìwọ̀nyí:
Awódélé wá kí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí
Àkànbí, àbúrò Aríyìíbí, tí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí nígbà tí ó ń sàìsànṣàìṣàn ní ó dúró fún ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbíàgóàgọ́ olópàáọlọ́pàá (ÌyenÌyẹn ni pé Àkàbí tí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí wòsàn ni ó dúró fún òun náà)
ojóọjọ́àwonàwọn ÒfíntótóỌ̀fíntótó wá sí ilé ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí, nnkan bí agogo mókànlá ni ó woléwọlé àwonàwọn Òfíntótó sì dé ilé rèrẹ̀ ní aago méjì kojákọjá ìséjúìṣẹ́jú méwàámẹ́wàá.
Nígbà tí Akin OlúsínàOlúṣínà àti Ilésanmí dé òdòọ̀dọ̀ ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí tí ó rò pé oògùn ni wónwọ́nseṣeòdòọ̀dọ̀ òun, àwonàwọn eboẹbọ tí ó kà fún wonwọn ni ìyá ewúréewúrẹ́ kan, egbèrúnẹgbẹ̀rún náírà ìgò epo kan, isuiṣu métamẹ́ta àti ìgàn asofunfunaṣọfunfun kan.
Akin Olúsínà mu emuẹmu ní ilé ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí AjéwoléAjéwọlé ni ó ra kòkó lówólówọ́ ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí. EgbèfàẸgbẹ̀fà náírà (N200.00) ni ó gbà ní owó kòkó náà.
 
8. ÀwonÀwọn ohun tí ó yeyẹ kí a seṣe àkíyèsí ní orí yìí ni ìwònyíìwọ̀nyí:
Láti lè momọ iye tí ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí gbà fún kòkó tí ó tà fún AjéwoléAjéwọlé, ogbónọgbọ́n ni wónwọ́n fi tan ÒsanyìnnínbíỌ̀sanyìnnínbí. WónWọ́n sosọ fún un pé enìẹnì kan ń robírọbí àti pé yóò nílò onísèègùnoníṣèẹ̀gùn.
OmoỌmọ odúnọdún méfàmẹ́fà ni OládiípòOládiípọ̀. Òun sì ni àbíkéyìnàbíkẹ́yìn Yéwándé
Bándélé jéjẹ́ omoọmọ odún méjomẹ́jọ. OmoỌmọ ÀsàkéÀṣàkẹ́ ni Jayéjayé kan ni ÀsàkéÀṣàkẹ́ máa ń wowọ àdìreàdìrẹ tàbí borokéèdì ó sì máa ń wowọ súwétasúwẹ́ta nígbà òtútù.
 
FawoléFawọlé: Ó wà lára àwonàwọn eniẹni tí ó wá wo OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ nígbà tí ara rè kò yá. Nígbà tí Akin Olúsínà seṣe ìwádìí nípa rèrẹ̀, èsì tí ó rí gbógbọ́ ni ìwònyíìwọ̀nyí:
WónWọ́n ní ìhà sáábó ni FáwoléFáwọlé máa ń gbe TinúkéTinúkẹ́ ni orúkoorúkọ omoọmọ rèrẹ̀.
 
Nípa asoaṣọ tí ó wòwọ̀ojóọjọ́ tí ó wá sí òdòọ̀dọ̀ OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́, eniẹni kan sosọasoaṣọ sáféètìsáfẹ́ẹ̀tì pèlúpẹ̀lú asoaṣọ òfì ni ó wòwọ̀. EniẸni kan sosọ pé sán-ányán ni asoaṣọ tí ó wòwọ̀ níwònníwọ̀n ìgbà tí ó ti jéjẹ́àwonàwọn omódéọmọ́dé kìí tètè gbàgbé nnkan, Akin OlúsínàOlúṣínà ní kí awónawọ́n bèèrè ìbéèrè nípá FáwoléFáwọlé lówòlọ́wọ̀ FólúkéFólúkẹ́ àti Bándélé.
 
FólúkéFólúkẹ́ sosọasoaṣọ sáféètìsáfẹ́ẹ̀tì ni ó wòwọ̀. Ó ní ó dé filà sán-ányán, ó wówọ́ bàtà aláwòaláwọ̀ funfun ràkòràkòràkọ̀ràkọ̀
Bándélé ni ó bomi fún FáwoléFáwọléojóọjọ́ tí ó wá sí òdòọ̀dọ̀ OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́.
FolúkéFolúkẹ́ojoojúmóojoojúmọ́ ni ÒsányìnnínbíỌ̀sányìnnínbí máa ń wá sódòsọ́dọ̀ OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ nígbà tí OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ń sàìsàn ó sì máa ń dúró di ìgbà tí wónwọ́n bá ń pèrun aléalẹ́ kí ó tó kúrò ní òdòọ̀dọ̀ rèrẹ̀. FolúkéFolúkẹ́ ní òun rí nnkan kan bí ológbò ní àpò rèrẹ̀ ni ojóọjọ́ kan.
Àlàó kò gbógbọ́ nípa eniẹni tí ó ń fi kókórókọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò nítorí pé ó lolọ sí ibì òkú ìyá BáyòBáyọ̀ojóọjọ́ náà.
Ìyá Bándélé ni eniẹni tí ó fi kókórókọ́kọ́rọ́ dan séèfù wò náà OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́sosọ òròọ̀rọ̀ eni tí ó fi kókórókọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò yìí fún Àlàó. Yéwándé náà kò sosọ fún un.
 
9. Igba náírà (N200.00) ni wónwọ́n bá ní ilé ÀsàkéÀṣàkẹ́, ìyenìyẹn ìyá Bándélé nígbà tí àwonàwọn Akin OlófìnỌlọ́fìn-íntótó yeyẹ ilé rèrẹ̀ wò. EniẸni tí ó fi kókórókọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò tí a ń sòròsọ̀rọ̀ rèrẹ̀ lókè ni ÀsàkéÀṣàkẹ́ ìyá Bándélé. folúkéfolúkẹ́ ni ó sosọ fún ìyá rèrẹ̀ÀsàkéÀṣàké ń fi kókórókọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò. ÀsàkéÀṣàkẹ́ máa ń kanra mómọ́ omodéọmọdé. AsoAṣọ òfì ni Yéwándé wòwọ̀ nígbà tó wónwọ́n ń seṣe ìwádìí yìí torí òtútù. OjóỌjọ́ kejì ojàọjà Ajágbénulékè ni ÀsàkéÀṣàkẹ́kókórókọ́kọ́rọ́ tí ó fi dán séèfù wò nínú yàrá rèrẹ̀. Àlàá, Àkin àti Ilésanmí fi kókórókọ́kọ́rọ́ náà dán séèfù wò, kò sí i.
LéyìnLẹ́yìn ìwádìí ti ojóọjọ́ yìí, Akin OlófìnỌlọ́fìn-íntótó àti ilésanmí padà sí Ìbàdàn. Ní ibi tí Akin ti dá mólòmọ́lò dúró nígbà tí o féfẹ́ eranẹran ìgbéìgbẹ́ ni bàbá alágbèdealágbẹ̀dẹ kan ti sosọ fún omoọmọ kan pé kí ó wò okòọkọ̀ náà. KóláKọ́lá ni orúkoorúkọ omoọmọ yìí. Orí yìí ní wónwọ́n ti wá momọ orúkoorúkọ omogeọmọge tí Akin OlúsínàOlúṣínà ra otíọtí fún nígbà tí wónwọ́n ń lolọIfèIfẹ̀ tí a ti ménumẹ́nusáájúṣáájú. OrúkoOrúkọ omogeọmọge yìí ni fìlísíà Olówólàgbà. A ó rí i ní iwájú pé filísíà Olówólàgbà yìí ni orúkoorúkọ mìíràn fún ìyàwo OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ tí ó jí owó Orímóògùnjé gbé.
Akin àti Ilésanmí wá filísíà yìí lolọ sí pètéèsì aláwò pupa rúsúsúsú. KóláKọ́lá ni ó ràn wónwọ́n lówólọ́wọ́ láti momọ ilé yìí. Akin àti Ilésanmí sun òdoọ̀dọ Fìlísíà mójúmọ́jú. Nígbà tí ilèilẹ̀ mómọ́, wónwọ́nPópóoláPópóọlá. Ó gbé wonwọn dé màpó.
 
10. Akin lolọ gbowó ní bànkì. Òun àti Ilésanmí ni wónwọ́n jojọ lolọ. Ní bánkì, wónwọ́n pàdé KóláKọ́lá. EnuẸnu rèrẹ̀ ni wónwọ́n ti gbógbọ́ pé Bínpé àbúrò fìlísíà féfẹ́ seṣe ìgbéyàwó ní GbòngánGbọ̀ngán. PópóoláPópóọlá gbé Akin, Ilésanmí àti KóláKọ́lá. Ní ònàọ̀nà, ní ibi tí alágbèdéalágbẹ̀dẹ́ ti fi KóláKọ́láokòọkọ̀ ní ìjelòó, wónwọ́nàwonàwọn méjì tí wónwọ́n ń jà Ògúndélé ni orúkoorúkọ alágbèdealágbẹ̀dẹ yìi. Òun ni ó ń bá Jìnádù jà. WónWọ́n gbá Adénlé tí ó féfẹ́ là là wónwọ́nèsèẹ̀sẹ̀ nínú. PópóoláPópóọlá tí ó jéjẹ́ olópàáọlọ́pàá ni ó pàsepàṣẹ pé kí wonwọnowóọwọ́ ìjà dúró tí wónwọ́nseṣe béèbẹ́ẹ̀.
 
Ohun tí ó fa ìjà tí Ògúndélé àti Jinádù ń jà ni pé Ògúndélé tí ó jé alágbèdealágbẹ̀dẹ rorọ kókórókọ́kọ́rọ́ kan fún jìnádù ní múrí métamẹ́ta (#60), Jìnádù san Múrí kan (#20) níbèníbẹ̀ ó ku múrí méjì (#40). Ògúndélé bínú nítorí pé Jìnádù kò tètè san múrí méjì tí ó kì. Jìnádù bínú nítorí pé ó sosọ pé Ògúndélé sin òun ní owó ní àárí àwùjoàwùjọ. Jìnádù sosọ pé Ògúndélé fi òrùkoòrùkọ èreẹ̀rẹ na òun. Nígbà tí KólàKọ́là sòsọ̀ kalèkalẹ̀ tí ó ń lolọ, ó gbàgbé àpò rèrẹ̀ sùgbónṣùgbọ́n wónwọ́n dá a padà fún un.
 
Nígbà tí Ain àti Ilésanmí ti Ìbàdàn tí wónwọ́n ti ń bòbọ̀ dé Ilé-IfèIfẹ̀, wónwọ́n lolọ sí ilé fáwoléfáwọlé Nígbà tí OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ń sàìsànṣàìsàn lówólọ́wọ́folásadéfọláṣadé 9tí àwa tún mòmọ̀ sí fìlísíà) wá sí IfèIfẹ̀, ó lò tó ojóọjọ́ métamẹ́ta dípò méjì tí ó máa ń lò télètẹ́lẹ̀. Ìpàdé omolébíọmọlẹ́bíwónwọ́n féfẹ́ seṣe gan-an ni ó tèlè mú un padà. YàtòYàtọ̀ sí ìgbà tí ìnáwó pàjáwùrù bá wà ojóọjọ́ karùn-ún kànùn-ún ni OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ máa ń mú owó nínú séèfù rèrẹ̀ nígbà tí ó wà láyé.
GégéGẹ́gẹ́ bí a ti sosọ télètẹ́lẹ̀, Yéwándé máa ń bá OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ mú owó nínú séèfù rèrẹ̀ sùgbónṣùgbọ́n ó tó osùoṣù kan sí ìgbà tí OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ tó kú tí ó ti rán an mú owó nínú rèrẹ̀ gbèyìn. OjóỌjọ́ ojàọjà ni ojóọjọ́OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ máa ń mú owó nínú séèfù rèrẹ̀ máa ń bóbọ́ sí. OjóỌjọ́ kérinkẹ́rinOrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ mú owó kéyìnkẹ́yìn nínú séèfù rèrẹ̀ ni ó kú. ÌyenÌyẹn ni pé ojàọjà dòladọ̀la ni ó kú OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ máa ń fún àwonàwọn ìyàwó rèrẹ̀ ní owó-ìná tí ó bá ti mówó. Níbi tí wónwọ́n ti ń seṣe ìwadìí yìí, Akin OlúsínàOlúṣínà ń fi ataare jobì. Túndé AtòpinpinAtọ̀pinpin ní kí àwonàwọn yeyẹ yàrá FolásadéFọláṣadé wò.
 
11. Ìsòrí kokànlákọkànlá yìí ni ó ti hàn gbangba pé FolásadéFọláṣadé, òkanọ̀kan nínú àwonàwọn ìyàwó Orímóògùn ni ó jí owó rèrẹ̀ gbé. Ó ní ìdí tí òun fi jí owó náà gbé nip é òun kò bímobímọ fún OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ òun kò sì féfẹ́ kì tòun ó gbé sílé rèrẹ̀ nítorí pé omoọmọ tì obìnrin bá bí fún okoọkọ ni wónwọ́n fi máa ń pín ogún okoọkọ náà ní ilèilẹ̀ Yorùbá. FolásadéFọláṣadé ni ó yí orúkoorúkọ padà tí ó di fìlísíà. Òun náà ni ó lolọ rorọ kókórókọ́kọ́rọ́ lódòlọ́dọ̀ bàbá àgbèdeàgbẹ̀dẹÀsàkéÀṣàkẹ́ fi dán séèfù wò.
 
 
#ÀwonÀwọn Èdá-Ìtàn
 
Akin OlúsínàOlúṣínà: Òun ni wónwọ́n máa ń pè ní Akin OlófìnỌlófìn-íntótó, omoọmọ OlúsínàOlúṣínà. Òun ni ó seṣe ìwádìí owó tí ó sonùsọnù. ÀròsoÀròsọ ni ó ti wokòwọkọ̀ lolọIfèIfẹ̀ láti lolọ seṣe ìwádìí owó náà. Fìlà rèrẹ̀bóbọ́ sílèsílẹ̀ nínú mótòmọ́tò tí ó wòwọ̀. DírébàDírẹ́bà okòọkọ̀ yìí kò momọ okòọkọ̀ wà dáadáa. Akin OlúsínáOlúṣíná férànfẹ́ràn eranẹran ìgbéìgbẹ́. Ó máa ń mutí. Ó máa ń jobì tó fi ataa sínú rèrẹ̀. Ó ní túbòmutúbọ̀mu ó sì máa ń fi owóọwọ́ pa á. Ó seṣe wàhálà púpòpúpọ̀ kí ó tó mòmọ̀FolásadéFọláṣadé tí ó tún ń jéjẹ́ filísíà nì ó jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kó.
 
FolásádéFoláṣádé: Òun ni ó jí owó OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kó. Kò bímobímọ fún OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. Ìdí nì yí tí ó fi jí owó rèrẹ̀ gbé. Ó ní kí ti òun má bàa jéjẹ́ òfo nílé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ ni ó jéjẹ́ kí òun jí owó rèrẹ̀ gbé. FolásadéFọláṣadé náà ni ó yí orúkoorúkọ padà sí fìlísíà Olówálàgbà. OrúkoOrúkọ yìí ni ó si fi lolọ fi owó pamópamọ́ sí bánkì. Gbòngán ni ó ń gbé sùgbónṣùgbọ́n gégégẹ́gẹ́ bíi fìlísíà, ó ní ilé sí Ibadan.
GégéGẹ́gẹ́ bíi fìlísíà, ÒgáỌ̀gá ni ó jéjẹ́ fún KóláKọ́lá Òwú ara súwétàsúwẹ́tà rèrẹ̀ tí ó já bóbọ́ síbi séèfù wà lára ohun tí ó ran Akin OlúsínàOlúṣínà lówólọ́wọ́ láti rí i mú. Ìwé ìfowópamóìfowópamọ́ rèrẹ̀ tí Akin OlúsínàOlúṣínàlówólọ́wọ́ KóláKọ́lá náà tún wà lára ohun tí ó ran Akin OlúsínàOlúṣínà lówólọ́wọ́.
FolásadéFọláṣadé wà lára àwonàwọnwónwọ́n bí séèfù lójú rèrẹ̀ ní ilé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́wonwọn kò bá nnkan kan níbèníbẹ̀. Kò sì jéwójẹ́wọ́ pé òun ni òun kó owó tí ó wà níbèníbẹ̀. Ó máa ń ti GbòngánGbọ̀ngán wá sí IfèIfẹ̀. Òun ni ìyàwó àfékéyìnàfẹ́kẹ́yìn foún OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. Tí ó bá wá láti GbòngánGbọ̀ngán, ó máa ń lò tó ojóọjọ́ márùn-ún ní IfèIfẹ̀ tàbí òsèọ̀sẹ̀ kan. Ilé oúnjeoúnjẹ ni Akin àti Ilésanmí ti kókókọ́kọ́ pàdé rèrẹ̀. LéyìnLẹ́yìn tí ó jiyán tán ní ilé olóúnjeolóúnjẹ yìí, ó mu ìgò otí kan àti àbòàbọ̀ nínú otíọtí tí Akin OlúsínàOlúṣínà rà.
 
Àkàngbé OrímóògùnjéỌrímóògùnjẹ́: Òun ni wónwọ́n jí owó rèrẹ̀ gbé tí Akin OlúsínàOlúṣínàseṣe ìwádìí rèrẹ̀. Àìsàn tí ó seṣe é tí ó fi kú kò ju ojóọjọ́ méwàámẹ́wàá lolọ. AbéAbẹ́ ìròríìrọ̀rí rèrẹ̀ ni kókórókọ́kọ́rọ́ ojú ńlá séèfù rèrẹ̀ máa ń wà. Inú séèfù yìí nì ó máa ń kó owó sí. Kìí yoyọ àwonàwọn kókórókọ́kọ́rọ́ ojú kékeré séèfù yìí. Tí wónwọ́n bá ti ilèkùn yàrá rèrẹ̀, wónwọ́n máa ń fi kókorókọ́kọrọ́ há orí àtérígbà níbi tí enikéniẹnikẹ́ni ti lè mú un. OrúkoOrúkọ múràn tí ó ń jéjẹ́ ni Bándélé. Ogóje náírà (#140), péré ni wónwọ́n bá nígbà tí ó kú tán. Kí ó tó kú ó ti ra ilèilẹ̀ tí yóò fi kólèkọ́lè. AjísafínníAjíṣafínní ni ó bá a dá sí òròọ̀rọ̀ ilèilẹ̀ tí ó rà náà. Owó ÒsúnlékèÒṣúnlékè ni ó ti rà á. EgbàátaẸgbàáta náírà (#6,000) ni ó ra ilèilẹ̀ náà.
 
Dúró: Dúró ni àkóbíàkọ́bí omoọmọ Àkàngbé OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. Ilé-èkóẹ̀kọ́ girama ni ó wà. OdúnỌdún kan ni ó kù kí ó jáde. Òun ni ó kokọ ìwé sí Akin OlúsínàOlúṣínà pé kí ó wá bá òun wádìí owó bàbá òun tí wonwọn kò rí mómọ́. Àdùnní ni orúkoorúkọ ìyá rèrẹ̀ òun nìkan ni ó sì bí fún bàbá rèrẹ̀. Àdùnní yìí tí kú ní odúnọdún métamẹ́ta sáájúṣáájú bàbá rèrẹ̀. OmoỌmọ odúnọdún métàdínlógúnmẹ́tàdínlógún (17) nì Dúró. Àbúrò mérinmẹ́rin ni ó ní. ÀwonÀwọn náà ni ÀdùkéÀdùkẹ́, OmówùmíỌmọ́wùmí, Oládípò àti Bándélé.
 
Àdùnní: Àdùnní ni ìyàwó tí OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́ kókókọ́kọ́ féfẹ́. Ó kú ní odúnọdún métamẹ́ta sáájú okoọkọ rèrẹ̀. Òun ni ó bí Dúró fún OrímóògùnjéOrímóògùnjẹ́. ÈgbónẸ̀gbọ́n ni ó jéjẹ́ fún Ilésanmí. OmoỌmọ ìlú kan náà nì òun àti Akin OlúsínàOlúṣínà.
 
*Kola Akinlade (1976), Owo Eje. Ibadan, Nigeria: Onibonoje Press and Book Industries (Nig. Ltd). Oju-iwe = 116