Michigan: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè ìṣọ̀kan Amẹ́ríkà
Content deleted Content added
New page: Michigan Okan ninu awon ipinle ti o loro ju ni ile Amerika ni Michigan. O fi egbe ti Canada ati awon great Lakes maraarun. Awon eniyan to n gbe ibe to 8, 875,000. Won n se kaa pupo ni...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 12:58, 24 Oṣù Kejì 2008

Michigan

Okan ninu awon ipinle ti o loro ju ni ile Amerika ni Michigan. O fi egbe ti Canada ati awon great Lakes maraarun. Awon eniyan to n gbe ibe to 8, 875,000. Won n se kaa pupo ni ipinle yii nitori pe won ni irin. Detroit je okan lara awon ilu pataki ti won ti n se kaa ni Michigan. awon ara ile Faranse ni o koko te Michigan do ni nnkan bii 1600. Awon Geesi gba a lowo won ni 1763. Michigan di ipinle kerindinlogbon ni ile Amerika ni 1837.