Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"

207 bytes added ,  17:48, 28 Oṣù Kejì 2008
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Sango moved to Sàngó)
[[Sango]]
 
'''Sàngó'''
 
Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ilee Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé sàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti pé Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.
 
2. Adeoye C. L. [1985] Igbagbo ati Esin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press
 
 
 
{{ekunrere}}
[[Category:Orisa]]
[[Category:Yoruba]]
 
 
[[bg:Шанго]]
[[de:Shango]]
[[en:Shango]]
[[es:Shango]]
[[it:Sango (divinità vuduista)]]
[[pl:Szango]]
[[pt:Xangô]]
[[ru:Шанго]]
[[sv:Shango]]