Maasai: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 15:
}}
 
'''Maasai''' je eya awon eniyan ni [[Apa Ilaoorun Afrika|Apailaoorun Afrika]]. Wón wà ní àdúgbò orílè èdè Tanzania àti Kenya, wón sì féè tó òké métàdínlógún ààbò ní iye. Èdè won ni OI Maa wón sì múlé gbe Samburu, Kikuyu, Kamba, Chaga, Meru abbl. Darandaran tààrà ni wón. won a sì máa sín ìlèkè gan-an. Ojó orí ni wón máa fi ń se ìjoba ní ilè yìí, obìnrin won kìí sìí pé ní oko sùgbón okùnrin gbódò ní owó lówó kí ó tó fé aya. Ní àsìkò ayeye pàtàkì, màálù ni wón máa ń fi rúbo.
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Maasai"