William Butler Yeats: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: W.B YEATS ==W.B. Yeats== A bí W.B. Yeats ní 1865. Ó kú ní 1939. Ó ko òpòlopò ewì. O gbà pé nnkan tí ó bá selè ní egbèrún méjì o...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 08:10, 16 Oṣù Kẹta 2008

W.B YEATS

W.B. Yeats

A bí W.B. Yeats ní 1865. Ó kú ní 1939. Ó ko òpòlopò ewì. O gbà pé nnkan tí ó bá selè ní egbèrún méjì odún kan ni yóò tún selè ní egberún méjì odún tí ó bá tún tèlé é.

EZRA POUND

Ezra Pound

A bí i ní 1885. Ó kú ní 1922. Ààrin gbùngùn ìwò-oòrùn Àméríkà ni wón ti bí i. Néfíù (nephew) ni ó je sí Longfellow tí ó jé akéwì pàtàkì. Òpòlopò ewì ni ó ko.

T.S. ELIOT

T.S. Eliot

Wón bí Eliot ní 1888. Ó kú ní 1965. Òun ni omo tí ó kéré jù nínú àwon omo tí òbí rè bí. St Lonis lórí Missiossippi ni wón ti bí i. Àwon ebí rè tún ní ilè ní Cape Anne ní New England. Ibè ni Ehot ti máa n lo lo ìsinmi nígbà tí ó wà ní omodé. Òpòlopò ewì ni Ehot ko.

W.H AUDEN

W.H. Auden

A bí Auden ní 1907. Ó kú ní 1973 Òpòlopò ewì ni ó ko. Ó kó lo, ó lo n gbé ní Àméríkà ní 1939. Ó sì n ko ewì náà níbè.