Èdè Swàhílì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
No edit summary
The areas where Swahili or Comorian is the indigenous language (dark green), official or national language (medium green), and trade language (light green). As a trade language, it extends some distance further to the northwest.
}}
''' Ede Swahili''' tabi '''Kiswahili'''(ni ede Kiswahili) je ede ni [[Afrika]].Ede naa je [[ede Bantu]] ti o gbooro ju lo fun iwulo ni iha [[Ila Oorun Afrika]].Pupo ninu awon eya ti o wa ni Ila Oorun Afrika, ni o n lo ede naa, gege bi ede Ibara soro.Lilo ede naa wopo julo lati Ariwa orile ede [[Kenya]] titi de Ariwa orile Ede [[Mozambique]], ati awon [[Erekusu]] ti o wa ninu [[okun India]],fun apere [[Zanzibar]] ati [[Pemba]], tabi [[Comoros]] ati [[Mayotte]].b'o tile je pe iye eniyan egbegberun marun{5 million} nikan ni o n lo ede naa gege bi ede abinibi,Iye apapo eniyan to gbo, ati ti o le lo ede naa fun ibanisoro laarin ara, to egbegberun Ogota[60Million} enuyaneniyan<ref>Irele 2010</ref>, ni Ila Oorun ati Aarin [[Orile Erekusu]] Afrika.
 
== Ìmò Eréfē ==
79

edits