Èdè Swàhílì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
kNo edit summary
Ìlà 27:
== Ìmò Eréfē ==
[[File:Swahili-pn.jpg|thumb|left|160px|b'o tile je pe [[itona kiko Larubawa]] ni a koko lo ni kiko Ede Swahili,[[itona kiko Latin]]ni ede naa n lo fun ikosile nisisiyii, eleyyi ti o di iwulo, nitori awon olupolongo fun Esin Kristi ati ijoba amunisin. kiko ti o jeyo ninu aworan yii je [[Adura oluwa]] ni itona ti esin katoliki.<ref>http://wikisource.org/wiki/Baba_yetu</ref>]]
Swahili je ede Bantu. pupo ninu awon Eya ti wa ni Eba odo Okun India, ni Ila Oorun Afrika ni o si n lo Ede naa.Pupo ninu awon oro ti o jeyo ninu Ede Swahili,lo ní orisun ninu Ede Larubawa, nitori Ibalopo ti o waye laarin awon Eya Bantu, ati awon Onisowo Larubawa, ti o wa ni eti bebe [[Zanj]] ati [[pásíà]] (Iran) ni Ila orun Afrika.Awon ede miran ti jeyo ninu awon oro Swahili ni Ede Jamani(German), Ede Potoki(Portuguese),[[Èdè Gẹ̀ẹ́sì]](English), ati Ede Faranse{French}, lati awon Ibalopo ti o waye larin awon onilo ede wonyii, ni nkan bi odun Ogorun marun (500) sehin.Ede Swahili ni oni ,ti di ede Keji, ni Ilo fun Egbegberun eniyan ni orile-ede meta ni Iha Ila Orun Afrika, Tansania, Kongo (DRC) ati Kenya, ni ibi ti ede naa ti je ede Ijoba.Ijoba Orile ede Uganda so ede naa di kiko ni gbogbo Ile Iwe alakobere, ni odun 1992.Bi o tile je pe igbese naa o sele bi won ti se ro, Ijoba orile ede naa so ede naa da Ede Ijoba no odun 1995, fun Imura s'ile ti [[Ìsọkan ti agbègbè Ilà Orùn Áfríkà]].Gbogbo eniyan orile-ede Komoros ninu okun India ni o le so Ede Swahili, tabi ede ti o fara pẹ Swahili, fun apẹẹrẹ [[Èdè Shíkọkmọ]](Comorian).Iye eniyan die si n lo ede na ni awon Orile Ede [[Burundi]], [[RuwandaRwanda]], ati Ariwa orile ede [[Sámbíà]]