Èdè Swàhílì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
kNo edit summary
Ìlà 27:
== Ìmò Eréfē ==
[[File:Swahili-pn.jpg|thumb|left|160px|b'o tile je pe [[itona kiko Larubawa]] ni a koko lo ni kiko Ede Swahili,[[itona kiko Latin]]ni ede naa n lo fun ikosile nisisiyii, eleyyi ti o di iwulo, nitori awon olupolongo fun Esin Kristi ati ijoba amunisin. kiko ti o jeyo ninu aworan yii je [[Adura oluwa]] ni itona ti esin katoliki.<ref>http://wikisource.org/wiki/Baba_yetu</ref>]]
Swahili je ede Bantu. pupo ninu awon Eya ti wa ni Eba odo Okun India, ni Ila Oorun Afrika ni o si n lo Ede naa. Pupo ninu awon oro ti o jeyo ninu Ede Swahili,lo ní orisun ninu Ede Larubawa, nitori Ibalopo ti o waye laarin awon Eya Bantu, ati awon Onisowo Larubawa, ti o wa ni eti bebe [[Zanj]] ati [[pásíà]] (Iran) ni Ila orun Afrika, ni bi odun Ogorun mejila sehin. Awon ede miran ti jeyo ninu awon oro Swahili ni Ede Jamani(German), Ede Potoki(Portuguese),[[Èdè Gẹ̀ẹ́sì]](English), ati Ede Faranse{French}, lati awon Ibalopo ti o waye larin awon onilo ede wonyii, ni nkan bi odun Ogorun marun (500) sehin.Ede Swahili ni oni ,ti di ede Keji, ni Ilo fun Egbegberun eniyan ni orile-ede meta ni Iha Ila Orun Afrika, [[Tànsáníà]], [[Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tòṣèlúaráìlú ilẹ̀ Kóngò]] ati Kenya, ni ibi ti ede naa ti je ede Ijoba.Ijoba Orile ede Uganda so ede naa di kiko ni gbogbo Ile Iwe alakobere, ni odun 1992. Bi o tile je pe igbese naa o sele bi won ti se ro, Ijoba orile ede naa so ede naa da Ede Ijoba no odun 1995, fun Imura s'ile ti [[Ìsọkan ti agbègbè Ilà Orùn Áfríkà]]. Gbogbo eniyan orile-ede Komoros ninu okun India ni o le so Ede Swahili, tabi ede ti o fara pẹ Swahili, fun apẹẹrẹ [[Èdè Shíkọmọ]](Comorian).Iye eniyan die si n lo ede na ni awon Orile Ede [[Bùrúndì]], [[Rùwándà]], ati Ariwa orile ede [[Sámbíà]]