Èdè Swàhílì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
kNo edit summary
|notice=IPA
}}
''' Ede Swahili''' tabi '''Kiswahili'''(ni ede Kiswahili) je ede ni [[Afrika]].Ede naa je [[ede Bantu]] ti o gbooro ju lo fun iwulo ni iha [[Ìlaòrùn Áfríkà]].Pupo ninu awon eya ti o wa ni Ila Oorun Afrika, ni o n lo ede naa, gege bi ede Ibara soro.Lilo ede naa wopo julo lati Ariwa orile ede [[Kenya]] titi de Ariwa orile Ede [[Mozambique]], ati awon [[Erekusu]] ti o wa ninu [[okun India]],fun apere [[Zanzibar]] ati [[Pemba]], tabi [[ComorosKòmórò]] ati [[Mayotte]].b'o tile je pe iye eniyan egbegberun marun{5 million} nikan ni o n lo ede naa gege bi ede abinibi,Iye apapo eniyan to gbo, ati ti o le lo ede naa fun ibanisoro laarin ara, to egbegberun Ogota[60Million} eniyan<ref>Irele 2010</ref>, ni Ila Oorun ati Aarin [[Orile Erekusu]] Afrika.
 
== Ìmò Eréfē ==
79

edits