Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Nnamdi Azikiwe"

8 bytes added ,  12:51, 6 Oṣù Kẹjọ 2008
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (robot Adding: fi:Nnamdi Azikiwe)
[[Image:zik.jpg|thumb|right|Nnamdi Azikiwe]]
Ologbe '''Nnamdi Azikiwe''' (November 16, 1904 – May 11, 1996) je omo orile ede [[Naijiria]], lati [[eya]] [[Ọmọ Ígbò|Igbo]] ni apa ila orun ile [[Naijiria]]. Okan ninu awon [[oloselu]] pataki ni Azikwe je ni Naijiria. Azikwe je Aare (President) akoko fun orile ede Naijiria leyin igbati Naijiria gba ominira ni odun [[1960]].
A bí i ní odúnọdún 1904. Ó kàwé ní calabar àti [[Èkó]]. Òun ni olóòtu, Morning Post West African Pilot. Ó di ènìyàn dúdú àkókóàkọ́kọ́ tí yóò jeje GovernorGomina-GeneralGbogbogbo fun [[Nigeria]] ní 1960. Ó se ìdásílè University of Nsukka. Ó kú ní odún 1996.