Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"

58 bytes added ,  13:21, 30 Oṣù Kẹfà 2012
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot Fífikún: fr:Shangô)
'''Sàngó''' Olukoso, Oko Oya.
 
YorùbáSango Je Okan lara Awon Orisa ti awon yorùbá n bò wọ́nwọ́a ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ilee Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé sàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti pé Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.
 
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bí Oba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
Anonymous user