Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Benin"

9 bytes added ,  22:11, 17 Oṣù Keje 2012
k
== Oruko ==
 
"Benin" gege bi oruko re ko ni ohunkohun se pelu [[Ilẹ̀ọba Benin]] tabi [[Ilu Benin]] ni Naijiria. Oruko re tele je [[Dahomey]] (Dan-ejo (snake),Homey-Ilu tabi Ile,Ilu awon ejo) ki a to yi si Orile-ede Olominira Omoilu ile Benin ni odun 1975 nitori pe egbe odo to wa un je [[Etiodo Benin]]. Won mu oruko yi nitoripe ko fi s'egbe kan larin gbogbo awon eya eniyan bi adota ti won wa ni ile Benin. Dahomey je oruko iluoba [[Fon]] ti ayeijoun, nitori eyi won ro pe ko to.
 
== Ìtàn ==