Èdè Ìdomà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{Infobox language |name=Ìdomà |speakers=600,000 |date=1991 |ethnicity=Ìdomà |region=Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Àrin Nigeria |map=Idoma.jpeg |familycol..."
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 06:59, 27 Oṣù Kẹjọ 2012

Èdè Ìdomà tàbí Idoma jẹ́ èdè ní Àrin Nàìjíríà (ní Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé). Èdè Idoma A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílè èdè Náígíríà. Àwon tí wón ń so èdè yìí jé igba méjì ati àádóta egbèrún. Àwon aládùgbóò rè ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Òpòlopò àwon Idoma ni wón je agbe. Wón si máa ń se àpónlé àwon baba ńlá won tí wón ti kú.

Ìdomà
Sísọ níÌpínlẹ̀ Bẹ́núé, Àrin Nigeria
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1991
Ẹ̀yàÌdomà
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀600,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3idu

Itokasi