Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Sádíìkì"

37 bytes added ,  11:16, 27 Oṣù Kẹjọ 2012
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (+Interwiki)
k
 
Omo ebi kan ni eleyii je fun ebi ede ile Aafirika kan ti oruko re n je Afro-Asiatic (Afuro-Esiatiiki). Awon ede ti o wa ninu Chadic yii to ogojo (160) awon ti o si n so awon ede wonyi to ogbon milionu. Awon ti o n so o bere lati iha ariwa Ghana (Gana) titi de aarin gbungbun Aafirika. Hausa ni gbajumo ju ninu awon ede ti o wa ni abe ipin Chadic. Oun nikan ni o wa ninu ipin yii ti o ni akosile ti o peye. Lara awon ede miiran ti o wa ni ipin yii a ti ri Anga, Kotoko ati Mubi.
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn èdè Áfríkà]]
 
[[ar:لغات تشادية]]
156

edits