Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 3:
'''Ìròjinlẹ̀ oníàgbéwò''' tabi '''irojinle alagbewo''' je idanwo ati [[critique|ayewo]] [[society|awujo]] ati [[culture|asa]], nipa lilo imo inu [[social sciences|awon sayensi awujo]] ati [[humanities|awon sayensi omoniyan]]. Oro yi ni itumo meji pelu awo orisun otooto ati itan: ikan bere lati inu [[sociology|oro-awujo]] ekeji lati inu [[literary criticism|iseagbewo onimookomooka]]. Eyi lo fa to je pe This has led to the very literal use of 'irojinle alagbewo' to ka si gbogbo irojinle to ba duro lori ayewo.
 
Ninu lilo oloro-awujo, irojinle alagbewo untoka si iru [[Marxist sociology|irojinle Marksisti]] pelu agbara lati koju awon ipa alaise Marksisti (fun apere iwe [[Friedrich Nietzsche]] ati [[Sigmund Freud]]).<ref>Outhwaite, William. 1988. ''Habermas: Key Contemporary Thinkers'' 2nd Edition (2009). p5. ISBN 9780745643281</ref> Agbara yi ni awon asemarksisti gbamugbamu unpe bi abuku ni [[revisionism (Marxism)|'iseatunyewo']]. Irojinle alagbewo odeoni dide lati inu eka to ta wa lati inu oro-awujo [[nonpositivist|alaiseonididaloju]] ti [[Max Weber]] ati [[Georg Simmel]], irojinle [[neo-Marxist|Marksisti tuntuntonituntun]] ti [[György Lukács|Georg Lukács]] ati [[Antonio Gramsci]], titi de ti awon to sepo mo [[Institute for Social Research|Ibi-Eko Iwadi Awujo Frankfurt]].
 
Pelu awon aserojinle ibi ti aun pe ni '"[[Frankfurt School|Ile-Eko Frankfurt]]" ni oro yi unsaba toka si: [[Herbert Marcuse]], [[Theodor Adorno]], [[Max Horkheimer]], [[Walter Benjamin]], ati [[Jürgen Habermas]]. Latowo eni to gbeyin yi ni irojinle oniagbewo ti tun jinna si ibere to ni ninu [[German idealism|iseboseye Jemani]] to si bo sunmo [[Pragmatism|iseoloungidi ara Amerika]]. Fife wa idi onirojinle fun "[[base and superstructure|opo titobi]]" asa to wa lati "ipile" eleroja nikan ni igbagbo Marksisti toseku ninu irojinle alagbewo igbalode.<ref>Outhwaite, William. 1988. ''Habermas: Key Contemporary Thinkers'' 2nd Edition (2009), p.5-8 (ISBN 9780745643281)</ref>