Orílẹ̀ èdè America: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
EmausBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.3) (Bot: Ìfikún bxr:Америка
Xqbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.3) (Robot: Modifying de:Vereinigte Staaten to de:Vereinigte Staaten von Amerika; cosmetic changes
Ìlà 74:
}}
 
'''Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà''' ''(I.A.A)'' tabi '''Àwọn Ìpínlẹ̀ Asokan''' (''I.A'' tabi ni Geesi: ''USA'' tabi ''US''), tàbí '''Amerika''' ni soki, jẹ́ orílé-èdè ijoba àpapò olominira pèlú [[iwe-ofin ibagbepo]] tí ó ni [[Awon Ipinle Amerika|adota ipinle]], [[agbegbe ijoba-apapo kan]] ati [[agbegbe merinla]], ti o wa ni [[Ariwa Amerika]]. Ilẹ̀ re fe lati [[Pacific Ocean|Òkun Pasifiki]] ni apa iwoorun de [[Òkun Atlántíkì]] ni apa ilaorun. O ni bode pelu ile [[Kanada]] ni apa ariwa ati pelu [[Meksiko]] ni apa guusu. Ipinle [[Alaska]] wa ni ariwaiwoorun, pelu Kanada ni ilaorun re ati [[Russia|Rosia]] ni iwoorun niwaju [[Bering Strait]]. Ipinle [[Hawaii]] je [[archipelago|agbajo erekusu]] ni arin Pasifiki. Orile-ede awon Ipinle Aparapo tun ni [[Territories of the United States|opolopo agbegbe]] ni [[Caribbean|Karibeani]] ati Pasifiki.
 
Pelu 3.79 egbegberun ilopomeji maili (9.83 million km<sup>2</sup>) ati iye to ju 309 egbegberun eniyan lo, awon Ipinle Aparapo je orile-ede totobijulo [[List of countries and outlying territories by total area|keta tabi kerin]] bii apapo iye aala, ati iketa totobijulo bii [[List of countries and outlying territories by land area|aala ile]] ati bi awon [[List of countries by population|olugbe]]. O je kan ninu awon orile-ede agbaye to ni [[Multiethnic society|opolopo eya eniyan]] ati [[multiculturalism|asapupo]], eyi je nitori ikoreokere lati opo awon orile-ede.<ref name="DD">Adams, J. Q., and Pearlie Strother-Adams (2001). ''Dealing with Diversity''. Chicago: Kendall/Hunt. ISBN 0-7872-8145-X.</ref> [[Economy of the United States|Okowo awon Ipinle Aparapo]] ni okowo orile-ede to tobijulo lagbaye, pelu idiye [[gross domestic product|GIO]] 2009 to je $14.3 egbegberunketa (idamerin [[List of countries by GDP (nominal)|GIO oloruko lagbaye]] ati idamarun GIO agbaye fun [[purchasing power parity|ipin agbara iraja]]).<ref name="IMF GDP">{{cite web|url=http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2009/02/weodata/weorept.aspx?sy=2006&ey=2009&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=111&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=64&pr.y=8|publisher=International Monetary Fund|title=World Economic Outlook Database|month=October|year=2009|accessdate=2010-04-27}}</ref><ref>The [[European Union]] has a larger collective economy, but is not a single nation.</ref>
 
Awon eniyan abinibi ti won wa lati [[Asia (orile)|Asia]] ti budo si ori ibi ti orile-ede awon Ipinle Aparapo wa loni fun egberun lopo odun. Awon olugbe [[Native Americans|Abinibi ara Amerika]] din niye gidigidi nitori arun ati igbogunti leyin [[European colonization of the Americas|ibapade awon ara Europe]]. Orile-ede awon Ipinle Aparapo je didasile latowo awon [[Thirteen Colonies|ileamusin metala ti Britani]] to budo si egbe Okun Atlantiki. Ni ojo 4 Osu Keje, 1776, won se [[United States Declaration of Independence|Ifilole Ilominira]], eyi kede eto won fun iko araeni ati idasile isokan alafowosowopo won. Awon ipinle asagun yi bori [[British Empire|Ileobaluaye Britani]] ninu [[American Revolutionary War|Ogun Ijidide Amerika]], eyi ni ogun alamusin fun ilominira akoko to yori si rere.<ref>Dull, Jonathan R. (2003). "Diplomacy of the Revolution, to 1783," p. 352, chap. in ''A Companion to the American Revolution'', ed. Jack P. Greene and J. R. Pole. Maiden, Mass.: Blackwell, pp. 352–361. ISBN 1-4051-1674-9.</ref> [[United States Constitution|Ilana-ibagbepo ile awon Ipinle Aparapo]] lowolowo je gbigba bi ofin ni ojo 17 Osu Kesan, 1787; itowobosi ni odun to tele so awon ipinle di apa orile-ede olominira kan na pelu ijoba apapo to lagbara. Awon [[United States Bill of Rights|Isofin awon Eto]], to ni atunse mewa si ilana-ibagbepo ti won semudaju awon eto ati ainidekun araalu, je titowobosi ni 1791.
 
Ni orundun 19th, awon Ipinle Aparapo gba ile lowo [[France]], [[Spain]], [[United Kingdom|Ileoba Aparapo]], [[Mexico]], ati Rosia, o si sefamora [[Republic of Texas|Ile Olominira Teksas]] ati [[Republic of Hawaii|Ile Olominira Hawaii]]. Ijiyan larin awon ipinle ni Guusu ati awon ipinle ni Ariwa lori awon eto awon ipinle ati igbegun [[slavery in the United States|oko eru]] lo fa [[American Civil War|Ogun Abele Amerika]] ti awon odun 1860. Isegun ti Ariwa dena ipinya, o si fa [[Thirteenth Amendment to the United States Constitution|opin oko eru]] ni Amerika. Nigba ti yio fi to awon odun 1870, okowo orile-ede awon Ipinle Aparapo ile Amerika ni eyi ti o tobijulo lagbaye.<ref>{{cite web|author=Maddison, Angus|url=http://www.ggdc.net/maddison/Historical_Statistics/horizontal-file_09-2008.xls|title=Historical Statistics for the World Economy|publisher=The Groningen Growth and Development Centre, Economics Department of the University of Groningen|year=2006|accessdate=2008-11-06}}</ref> [[Spanish–American War|Ogun Spein ati Amerika]] ati [[World War I|Ogun Agbaye Akoko]] so Amerika di orile-ede alagbara ologun. Leyin [[World War II|Ogun Agbaye Keji]] o di orile-ede akoko to ni ifija inuatomu, o si tun di omo egbe tikoye ni [[United Nations Security Council|Ileigbimo Abo Agbajo awon Orile-ede Aparapo]]. Opin [[Cold War|Ogun Koro]] ati [[Soviet Union|Isokan Sofieti]] mu ki awon Ipinle Aparapo o di [[superpower|orile-ede alagbara]] nikan to ku. Amerika siro fun idameji ninu marun inawo ologun lagbaye be sini o tun je akopa asiwaju ninu okowo, oloselu ati asa lagbaye.<ref>{{cite web|author=Cohen, Eliot A.|url=http://www.foreignaffairs.com/articles/59919/eliot-a-cohen/history-and-the-hyperpower|title=History and the Hyperpower|work=Foreign Affairs|date=July/August 2004|accessdate=2006-07-14}} {{cite news|url=http://news.bbc.co.uk/2/hi/americas/country_profiles/1217752.stm|title=Country Profile: United States of America|publisher=BBC News|date=2008-04-22|accessdate=2008-05-18}}</ref>
 
== Orisun itumo ==
Ni 1507, [[Martin Waldseemüller]] [[cartography|ayamaapu]] ara Jemani pese maapu lori ibi to ti pe oruko awon ile ti won wa ni [[Western Hemisphere|Ibiilaji Apaiwoorun]] bi [[Americas|"Amerika"]] lati inu oruko oluwakiriri ati ayamaapu ara Italia [[Amerigo Vespucci]].<ref>{{cite web|url=http://www.usatoday.com/news/nation/2007-04-24-america-turns-500_N.htm?csp=34|title=Cartographer Put 'America' on the Map 500 years Ago|work=USA Today|date=2007-04-24|accessdate=2008-11-30}}</ref> Awon ibiamusin Britani tele metala koko lo oruko orile-ede yi ninu [[United States Declaration of Independence|Ifilole Ilominira]], bi "Ifilole alafenuko awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("unanimous Declaration of the thirteen united States of America") to je gbigba mu latowo "Awon Asoju awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("Representatives of the united States of America") ni ojo 4 Osu Keje, 1776.<ref>{{cite web|url=http://www.archives.gov/exhibits/charters/charters.html|title=The Charters of Freedom|publisher=National Archives|accessdate=2007-06-20}}</ref> Ni ojo 15 Osu Kokanla, 1777, Ipejo Olorile Keji gba awon Ese-oro Ikorapapo, to so pe, "Oruko Ijekorapapo yi yio je 'Awon Ipinle Aparapo ile Amerika'" ("The Stile of this Confederacy shall be 'The United States of America.'") Awon iwe adehun lari Fransi ati Amerika odun 1778 lo "Awon Ipinle Aparapo ile Ariwa Amerika ("United States of North America"), sugbon lati ojo 11 Osu Keje, 1778, "Awon Ipinle Aparapo ile Amerika" ("United States of America") lo je lilo lori awon owo fun pasiparo, latigbana eyi lo ti je oruko onibise re.<ref>{{cite web|author=McClure, James|url=http://www.ydr.com/ci_9569289|title=A Primer: The 'First Capital' Debate|publisher=YDR.com|date=2008-06-12|accessdate=2010-07-26}}</ref>
 
Ni ede Yoruba "Orile-ede Amerika" tabi "Amerika" lasan loruko to wopo. A tun le lo lo "U.S." tabi "USA".
Ìlà 102:
=== Ojuojo ===
[[Fáìlì:Climatemapusa2.PNG|thumb|Maapu ojuojo ni Amerika]]
Ojuojo duro lori ibudo. Lati ileolooru ni [[Florida]] titi de [[tundra]] ni [[Alaska]]. Opo ibi ni won ni ooru ni igba eerun ati otutu ni igba oye. Awon ibomiran tun wa bi [[California]] ti won ni ojuojo [[Mediterranean climate|Mediteraneani]]. Ojuojo oloro ko wopo. Awon ipinle ti won bode mo [[Gulf of Mexico|Ikun-omi Meksiko]] ni iji are prone to hurricanes, and most of the world's tornadoes occur within the country, mainly in the Midwest's Tornado Alley.<ref>{{cite web|author=Perkins, Sid|url=http://www.sciencenews.org/articles/20020511/bob9.asp|archiveurl=http://web.archive.org/web/20070701131631/http://www.sciencenews.org/articles/20020511/bob9.asp|archivedate=2007-07-01|title=Tornado Alley, USA|accessdate=2006-09-20|date=2002-05-11|work=Science News}}</ref>
 
=== Awon irueweko ati irueranko ===
Ìlà 169:
[[cy:Unol Daleithiau America]]
[[da:USA]]
[[de:Vereinigte Staaten von Amerika]]
[[diq:Dewletê Amerikayê Yewbiyayey]]
[[dsb:Zjadnośone staty Ameriki]]