Nítrójìn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
{{Infobox nitrogen}}
'''Nítrójìn''' tàbí '''Náítrójìn''' ni [[ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà]] kan tó ní àmì-ìdámọ̀&nbsp;'''N''' àti [[nọ́mbà átọ̀mù]]&nbsp;7. Nítrójìn bíi ẹ́límẹ̀ntì jẹ́ ẹ̀fúùfù [[diatomic|átọ̀mùméjì]] aláilawọ̀, aláìlóòórùn, aláìní-ìtọ́wò àti [[inert|aláìkópa]] ní [[standard conditions|ìgbà onídéédéé]], tó jẹ́ 78.09% gẹ́gẹ́bí ìkùnnú [[Earth's atmosphere|ojúòrunojúọ̀run Ayé]].<ref name="Gray" >{{cite book|last=Gray|first=Theodore|title=The Elements: A Visual Exploration of Every Known Atom in the Universe|year=2009|publisher=Black Dog & Leventhal Publishers|location=New York|isbn=978-1-57912-814-2}}</ref> Nítrójìn jẹ́ wíwárí gẹ́gẹ́bí ohun inú afẹ́fẹ́ yíyàtọ̀, látọwọ́ oníṣègùn ará Skọ́tlàndì [[Daniel Rutherford]], ní 1772. Nítrójìn wà nínú ẹbí àwọn [[pnictogen|pníktójìn]].
 
Nítrójìn jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì tó wọ́pọ̀ nínú àgbálá-ayé, estimated at about seventh in total abundance in our [[Milky Way|galaxy]] and the [[Solar System]]. It is synthesised by fusion of carbon and hydrogen in supernovas. Due to the volatility of elemental nitrogen and its common compounds with hydrogen and oxygen, nitrogen is far less common on the rocky planets of the inner Solar System, and it is a relatively rare element on Earth as a whole. However, as on Earth, nitrogen and its compounds occur commonly as gases in the atmospheres of planets and moons that have atmospheres.