Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
'''Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù''' ni [[group (periodic table)|ẹgbẹ́ tábìlì ìdásìkò]] kan tó ní [[kárbọ̀nù]] ('''C'''), [[silicon|sílíkọ́nù]] ('''Si'''), [[germanium|jẹ́rmáníọ́mù]] ('''Ge'''), [[tin|tanganran]] ('''Sn'''), [[lead|òjé]] ('''Pb'''), àti [[flerovium|flẹ́rófíọ́mù]] ('''Fl''').
 
===Kẹ́míkà===
Bi àwon egbe yioku, àwon elimenti inu egbe yi ni eto bi [[electron configuration|itolera elektronu]] wo se ri, agaga igba to bosode, eyi unkopa ninu iwa kemika won:
 
{| class="wikitable" border="1" cellpadding="3" cellspacing="0"
|-
![[Atomic number|Z]] !! [[Chemical element|Ẹ́límẹ̀ntì]] !! [[Electron shell|Iye elektronu ninu igba kookan]]
|-
| 6 || [[Carbon]] || 2, 4
|-
| 14 || [[Silicon]] || 2, 8, 4
|-
| 32 || [[Germanium]] || 2, 8, 18, 4
|-
| 50 || [[Tin]] || 2, 8, 18, 18, 4
|-
| 82 || [[Lead]] || 2, 8, 18, 32, 18, 4
|-
| 114 || [[Flerovium]] || 2, 8, 18, 32, 32, 18, 4 (predicted)
|}