Ìtúká onítítànyindin: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
[[File:Alpha Decay.svg|thumb|[[Alpha decay|Ìtúká álfà]] jẹ́ àpẹrẹ kan irú is one example type of [[radioactivity|ìtúká títànyindin]], nibi ti [[atomic nucleus|nukleu atomu]] kan ti tu [[alpha particle|alfa alaratintinni]] kan sita, bi bayi to yirapada (tabi 'tuka') di atomu to din ni [[mass number|nomba atojoakojo]] 4 ati to din ni [[atomic number|nomba atomu]] 2. Orisi iru ituka miran lo tun se e se.]]
{{Nuclear physics}}
'''Ìtúká onítítànyindin''' tabi '''ítuka titanyindin''' tabi '''ituka radioaktifu''' ni igbese nibi ti [[atomic nucleus|nukleu atomu]] kan ti atomu ti ko ni iduro lese pofo okun-inu nipa yiyojade awon alaratintinni toun je sisodi ioni ([[ionizing radiation|iranka ijeonisisodiioni|]]). Awon orisirisi iru ituka titanyindin lowa. Ituka, tabi ipofo okun-inu, unsele nigbati atomu kan to ni iru nukleu kan, to unje ''[[radionuclide|radionuklidi]] obi'', yirapada di atomu to ni nukleu kan ni ipoaye to yato, tabi to di nukleu oto to ni iye [[proton]] ati [[neutron]] oto. Eyi to wu ninu awon yi ni o unje ''nuklidi omo''. Ninu awon ituka miran obi ati omo je [[chemical element|elimenti kemika]] otooto, nitori eyi igbese ituka fa [[nuclear transmutation|iyirapada nukleu]] wa (ida atomu elimenti tuntun).