Kẹ́místrì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Chauahuasachca ṣeyípòdà ojúewé Kẹ́místrìÌpògùn lórí àtúnjúwe
kNo edit summary
Ìlà 1:
[[Image:Chemicals in flasks.jpg|thumb|right|Chemicals in flasks (including Ammonium hydroxide and Nitric acid) lit in different colors]]
{{sáyẹ́nsì}}
'''Kẹ́místrìÌpògùn''' tí ṣe ẹ̀ka [[physical science|sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá]], jẹ́ ẹ̀kọ́ìwádìí ìkósínú, ìní àti ìwùwà ohun èlò.<ref name=definition>{{cite web|url=http://chemweb.ucc.ie/what_is_chemistry.htm |title=What is Chemistry? |publisher=Chemweb.ucc.ie |date= |accessdate=2011-06-12}}</ref><ref>[http://dictionary.reference.com/browse/Chemistry Chemistry]. (n.d.). Merriam-Webster's Medical Dictionary. Retrieved August 19, 2007.</ref> Kẹ́místrì únsọ nípa àwọn [[átọ́mù]] àti ìbáraṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn átómù míràn, àgàgà pẹ̀lú àwọn ìní àwọn [[chemical bond|ìsopọ̀ kẹ́míkà]]. Kẹ́místrì tún úndálórí àwọn ìbáraṣepọ̀ láàrin àwọn átọ́mù (tàbí ọ̀pọ̀ àwọn átọ́mù) àti orísirísi irú okun (f.a. àwọn ìdaramọ́ra f fọ́tòkẹ́míkà, àwọn ìyípadà nínú ojúwà èlò, ìyàsọ́tọ̀ àwọn àdàlú, àwọn ìní pólímẹ̀r, at.b.b,lọ).
 
Kẹ́místrì únjẹ́ pípè nígbà míràn bíi "[[the central science|sáyẹ́nsì agbàrin]]" nítorípé ó so ìṣeẹ̀dá mọ́ àwọn [[natural science|sáyẹ́nsì onítaládánidá]] míràn bíi [[geology|Jẹ́ọ́lọ́jì]] àti [[biology|baolọ́jì]].<ref>Theodore L. Brown, H. Eugene Lemay, Bruce Edward Bursten, H. Lemay. ''Chemistry: The Central Science''. Prentice Hall; 8 edition (1999). ISBN 0-13-010310-1. Pages 3-4.</ref><ref>Chemistry is seen as occupying an intermediate position in a hierarchy of the sciences by "reductive level" between physics and biology. See Carsten Reinhardt. ''Chemical Sciences in the 20th Century: Bridging Boundaries''. Wiley-VCH, 2001. ISBN 3-527-30271-9. Pages 1-2.</ref> Kẹ́místrì jẹ́ ẹ̀ka [[physical science|sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá]] sùgbọ́n [[Difference between chemistry and physics|ó yàtọ̀ sí físíksì]].<ref>[http://www.springerlink.com/content/k97523j471763374/ Is chemistry a branch of physics? a paper by Mario Bunge]</ref>