Nítrójìn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
{{translate}}
{{Infobox nitrogennítrójìn}}
'''Nítrójìn''' tàbí '''Náítrójìn''' ni [[ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà]] kan tó ní àmì-ìdámọ̀&nbsp;'''N''' àti [[nọ́mbà átọ̀mù]]&nbsp;7. Nítrójìn bíi ẹ́límẹ̀ntì jẹ́ ẹ̀fúùfù [[diatomic|átọ̀mùméjì]] aláilawọ̀, aláìlóòórùn, aláìní-ìtọ́wò àti [[inert|aláìkópa]] ní [[standard conditions|ìgbà onídéédéé]], tó jẹ́ 78.09% gẹ́gẹ́bí ìkúnnú [[Earth's atmosphere|ojúọ̀run Ayé]].<ref name="Gray" >{{cite book|last=Gray|first=Theodore|title=The Elements: A Visual Exploration of Every Known Atom in the Universe|year=2009|publisher=Black Dog & Leventhal Publishers|location=New York|isbn=978-1-57912-814-2}}</ref> Nítrójìn jẹ́ wíwárí gẹ́gẹ́bí ohun inú afẹ́fẹ́ yíyàtọ̀, látọwọ́ oníṣègùn ará Skọ́tlàndì [[Daniel Rutherford]], ní 1772. Nítrójìn wà nínú ẹbí àwọn [[pnictogen|pníktójìn]].