Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
[[Fáìlì:Periodic table.svg|450px|thumbnail|right|[[Tábìlì ìgbà]] awon apilese egbo]]
'''Ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà''' (chemical element) kan tabi '''ẹ́límẹ̀ntì''' ni soki ni iru [[átọ́mù]] ti [[nomba atomu]] re n fi han (iye [[àkọ́wá|protoni]] to wa ninu [[inuikunNúkléù atomuátọ̀mù|nukleu]] re).
 
Apere elimenti to gbajumo ni [[háídrójìn]], [[náítrójìn]] ati [[kárbọ̀nù]]. Ni apapo 118 ni iye awon apilese ti ati se awari won titi de odun 2007, ninu awon eyi 94, eyun [[plutoniumu]] ati ni sale lo, wa fun ra ara won ni orile aye.