Ìsopọ̀ kẹ́míkà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
'''Ìsopọ̀ kẹ́míkà''' ni ìfàmọ́ra láàrin àwọn [[átọ̀mù]] tó gba ààyè ìdá àwọn [[chemical substance|kẹ́míkà]] tí wọ́n ní átọ̀mù méjì tàbí mẹ́ta. Ìsopọ̀ náà sẹlẹ̀ nítorí [[electrostatic force|agbára ẹlẹktrostátìkì]] ìfàmọ́ra láàrin àwọn àgbéru olódì, bóyá láàrin àwọn [[electron|ẹ̀lẹ́ktrọ̀nù]] àti [[Atomic nucleus|núkléù]], tàbí gẹ́gẹ́bí ìdá ìfàmọ́ra [[dipole|etíméjì]]. Agbára àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà jẹ́ orísirísi; àwọn "ìsopọ̀ líle" bíi [[covalent bond|àjọfagbáradìmú]] tábí [[ionic bond|íónì]] wà àti àwọn "ìsopọ̀ dídẹ̀" bíi [[intermolecular force#Dipole-dipole interactions|ìbáṣepọ̀ etíméjì sí etíméjì]], [[London dispersion force|agbara ìfónkáìfọ́nká London]] àti [[hydrogen bonding|ìsopọ̀ háídrójìn]].