Íónì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
'''Íónì''' je [[atom|atomu]] tabi [[molecule|horo]] kan ni inu ibi ti iye apapo awon [[electron|elektronu]] ko dogba mo iye apapo awon [[proton|protonu]], bi be ti atomu na yio ni [[electric charge|agberu itanna]] to seku to je didaju tabi lilodi. The word ''Ioni'' wa lati oro ede [[Greek language|Griiki]] ἰόν (tto tumosi "unsoo rinso"), o si koko je lilo latowo asefisiksi [[Michael Faraday]] fufun awon ohun ti wowon unlo labe iwo itanna larin awon [[electrode|elektrodu]] ninu iyosomi kan, nigbati [[electric field|ayika itanna]] kan ba je mimulo mo.
 
Ti atomu adogba kan ba pofo elektronu kan tabi jubelo, yio ni agberu siseku didaju, eyi ni a unpe ni [[Íónì#Àwọn íónì àti kátíónì|kationi]]. Ti atomu kan ba jere elektronu, yio ni agberu siseku lilodi, a si unpe ni [[Íónì#Àwọn íónì àti kátíónì|anioni]]. Ioni kan to ni atomu kan soso ni a unpe ni ioni atomu tabi [[monoatomic ion|oniatomukan]]; to ba ni atomu meji tabi jubelo, a unpe ni ioni [[molecular|onihoro]] tabi [[polyatomic ion|oniatomupupo]].
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Íónì"