Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Áljẹ́brà onígbọrọ"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
[[File:Linear subspaces with shading.svg|thumb|250px|right|A line passing through the [[origin (mathematics)|origin]] (blue, thick) in [[Euclidean space|'''R'''<sup>3</sup>]] is a linear subspace, a common object of study in linear algebra.]]
 
'''Aljebra gbigboro''' (linear algebra) je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon [[atokaona]] (vector), [[aaye atokaona]] (vector space), [[maapu alatele]] (linear map) ati awon [[ona idogba alatele]] (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi [[aljebra]] alatele wulo lopolopo ninu [[aljebra afoyemo]] ati [[agbeyewo alabase]] (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon [[sayensi aladabaye]] ati [[sayensi awujo]] nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).