Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Àwọn ọmọ Yorùbá"

k
Bot: Ìdípò ìkọ̀rọ̀ oníaraẹni (-],[ +], [)
k (Bot: Migrating 3 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q190168 (translate me))
k (Bot: Ìdípò ìkọ̀rọ̀ oníaraẹni (-],[ +], [))
|related-c= [[Bini people|Bini]], [[Nupe]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ebira]]
}}
'''Awon omo Yoruba''' ti a pe ni eniyan Yoruba ni ibi yii po gan-an ni. Ile Yoruba ni pupo ninu won wa ni ipinle Edo, Ekiti, Eko, Kwara, Kogi Ogun, Ondo, Osun, Oyo; atiwipe omo Yoruba wa ni Bene ([[Dahomi]]), Saro ([[Sierra Leone]]) ati [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[U.S.A.]] ati Venezuela. Awon Yoruba ni won se ipo keta ni pipo ni ile [[Naijiria]].
 
Awon Yoruba je awon eniyan kan ti ede won pin si orisirisi. Awon ipin yii ni a nri; a maa lo ipin ede lati fi pe'ede wa ti nse bi ti "americas"; "ekiti"; "eko"; "ijebu"; "ijesha"; "ikale"; "oyo"; ati bebe lo. Laarin eyi, la sii tun ni ede ifo ti nse apere ede to nipin si awon ipin ede ti o po.